agan be vile igbimo asofin : omo egbe alakuko fake kori

8
Agan Be Vile Igbimo Asofin : Omo Egbe Alakuko Fake Kori: Awon Orao AG Binu Jade EKO- Agan be sil? ninu ilc igbimo A$ofin t i Ijijba Apapp§e ni owurp ana nigbati gbogbo awpn asoju li o je pmo egbe Alakuko pelu awpn 9 m 9 egbe Afenifyre (A.G,) binu li iie igbimo na silo, gbo- gbo wpn si ko iwc wpn, nwpn si luka nip Alaga Igbimo na, Albaji Ibrahim Jalo. lori nipa prp li pkan ninu awpn pmo egbe o$clu kan NPC l i s e Minisiia alamojuto eto ise AJE Ijpba Apapose , Alhaji Wa- ziri Ibrahim, so lori gbogbo enia li nwpn ka (Cer, sus) I.akiri ilc Nigeria Ian bi nkan o>u kcjc li nwpn ko le gbe iypri re si gbangba. Ajiluka Eleti-Ofe ni gbara li awon asoju yi li dc ile igbim;. na ni owur9 ana ni okan ninu won. Prince Abbey lati Qwcrri dide li o 59 fun alaga igbi mo wi pc awon le ki o pa is? ojo na li ki a\vpn le fenu k a n or? li Alhaji Waziri so, ni ijerin lori awon iiNJ.A-K.IICA (census) ki awpn le mp ibiti aivpn gbe nip lori prp na. Alaga na ko jalg, c I e y i ni o mu ki gbogbo won luka mo lori. Gbara li nwon li jade ni Olukuiuku egbc o$ciu li 0 wa ninu ile Igbimp Da Ip $c ipade. ninu cyili nwpn $c ipiunu nla kan wipe awpn ko ni igbakele lori ise Minisiia Alhaji Waziri pelu Oyinbo akania, Qgbjni Warren mp. Awpn i? ki Ijpba wa Oyiubo 11a kuro nil.ii ni kiakiu. Bi bp kp awpn ko hi pada silo igbimp oa. Okan ninu awpn aluypnusp Minisiia pgbv piup Aiakukp (NCNC) ti o ftp da si, nwpn ni ki o fi lire se lirp. OGBFNI MADOJUTOFA PA ITAN FUN OLOYE OJIKUTU: O Ni Oko-Eru Ni O Fe Ko Awon Lo Eyi ni csi prp Oloye Yekinni Ojikutu li awpn pmo egbe alapata eran I’Eko sp wipe a w 9 n r 9 loye ati pe ki 0 ko gbogbo iwc pgbe wa Pin Olori tilun, Qgbeni Lawaiii MadOjUtpla. Oloye Ojikutu, 0 tisp oko si wa, o si ye ki awa na sp oguluiu lu e sugbpn a ko n i s e be, idi prp ni ao In ye gbogbo cnyin ti c nka prpwana. Oloye Ojikutu si wa 11i ilc iwc nigbaf a da egbe alapata gran sile I fcko . LAGOS AMD EBUTE- METTA BUTCHERS' UNION ni a npc orukp egbe na Ologbc SUNMQNU AILARA ni Daddy A l a j a Sixeet ni Okc-Arin ni buba egbg na pelu Qgbpni B.B. Salami ti a fi *e akpwe. Lphin igbati ise apata erun di gbete ni iwp Oloye Oiikuiu 10 da egbe lire sile ti o si sp n i LAGOS WHOLESALE and RETAIL BUTCHERS' UNION. Egbe agba n tiwa si je si ti Oloye Ojikutu yi. Egbe wa na li o si dide si prp rogbodiyan iye bayi (Food control) ni eni lati la eran de ti nwpr. se I o f i a ni pdun 1942 nigba OGUN AGBAIYE. (Wo iyoku loju ewe keji) \won Si Gbongan Glover Lana EKO -Ilc apejo awpn ara E .0 l i gbogbo nyin m 0 pipe r? ni Glover Memo- rial llall ti nwpn ti tun tun kp ni nwpn pa Go- mina-agba Qlpla Dokila Mnamidi Azikiwe wipe ki o wa si ni ana pjo Jimp loju gbogbo awpn enia pa- taki palaki lpkunrin ati lobinrin. Qke-mf ta-o-le-pdggE a-a Jp ponun (£75, 000) ni nwpn fi kp ile gbpagan na, o si gba egbydpgbpn enia, yatp si ile ti alijp, oririsi nkan mere-mere ni nwpn iisi ile tuntun na. Olpla Dokila KoPowo- rpla Abaypmi ti?e o 1 0 ri awpn olutpju ile na ni o fi kpkprp iyebiyc le Gorni- na- -agba 'na Ipwp ni irpiv ana pe ki 0 fi si ile na.

Upload: others

Post on 31-Jul-2022

0 views

Category:

Documents


0 download

TRANSCRIPT

Page 1: Agan Be Vile Igbimo Asofin : Omo Egbe Alakuko Fake Kori

A g an Be V ile Ig b im o A sofin :

Omo Egbe Alakuko Fake Kori: Awon Orao AG Binu Jade

E K O - Agan be sil? ninu ilc igbimo A$ofin t i Ijijba Apapp§e ni owurp ana nigbati gbogbo awpn asoju li o je pmo egbe Alakuko pelu awpn 9 m 9 egbe Afenifyre (A.G,) binu li iie igbimo na silo, gbo­gbo wpn si ko iwc wpn, nwpn si luka nip Alaga Igbimo na, Albaji Ibrahim Jalo. lori nipa prp li pkan ninu awpn pmo egbe o$clu kan NPC l i s e Minisiia alamojuto eto ise AJE Ijpba Apapose , Alhaji W a- ziri Ibrahim, so lori gbogbo enia li nwpn ka (Cer, sus) I.akiri ilc Nigeria Ian bi nkan o>u kcjc li nwpn ko le gbe iypri re si gbangba.

A jiluka Eleti-Ofe ni gbara li awon asoju yi li dc ile igbim;. na ni owur9 ana ni okan ninu won. Prince Abbey

lati Qwcrri dide li o 59 fun alaga i g b i m o w i p c awon le ki o pa is? ojo na li ki a\vpn le fenu k a n or? li Alhaji Waziri so, ni ijerin lori awon iiNJ.A-K.IICA (census) ki awpn le mp ibiti aivpn gbe nip lori prp na. Alaga na ko jalg, c I e y i ni o mu ki gbogbo won luka mo lori.

Gbara li nwon li jade ni Olukuiuku egbc o$ciu li 0 wa ninu ile Igbimp Da Ip $c ipade. ninu cyili nwpn $c ipiunu nla kan wipe awpn ko ni igbakele lori ise Minisiia Alhaji Waziri pelu Oyinbo akania, Qgbjni Warren mp. Awpn i? ki Ijpba wa Oyiubo 11a kuro nil.ii ni kiakiu. Bi bp kp awpn ko hi pada silo igbimp oa. Okan n i n u awpn aluypnusp Minisiia pgbv piup Aiakukp (NCNC) ti o ftp da si, nwpn ni ki o fi lire se lirp.

OGBFNI MADOJUTOFA PA IT AN FUN OLOYE OJIKUTU:

O Ni Oko-Eru Ni O Fe Ko Awon LoEyi ni csi prp Oloye Yekinni Ojikutu li awpn

pmo egbe alapata eran I’Eko sp wipe a w 9 n r 9 loye ati pe ki 0 ko gbogbo iwc pgbe wa Pin Olori tilun, Qgbeni Lawaiii MadOjUtpla.

Oloye Ojikutu, 0 tisp oko si wa, o si ye k i awa na sp oguluiu lu e sugbpn a ko n i s e be, idi prp ni ao In ye gbogbo cnyin ti c nka prpw ana.

Oloye Ojikutu si wa 11 i ilc iwc nigbaf a da egbe alapata gran sile I fcko . LAGOS AMD EBUTE- M ETTA BUTCHERS' UNION ni a npc orukp egbe na Ologbc SUNM QNU A ILA R A ni Daddy A l a j a Sixeet ni Okc-Arin ni buba egbg na pelu Qgbpni B.B. Salami ti a fi *e akpwe.

Lphin igbati ise apata erun di gbete ni iwp Oloye Oiikuiu 10 da egbe lire sile ti o si s p n i LAGOS W HOLESALE and RETAIL BUTCHERS' UNION. Egbe agba n tiwa si je si ti Oloye Ojikutu yi. E g b e wa na li o si dide si prp rogbodiyan iye bayi (Food control) ni eni lati la eran de ti nwpr. se I o f i a ni pdun 1942 nigba OGUN AGBAIYE.

(Wo iyoku loju ewe keji)

\ w o n Si G b o n g an G lo v e r Lana

EKO -I lc apejo awpn ara E .0 l i gbogbo nyin m 0 pipe r? ni Glover Memo­rial lla ll ti nwpn ti tun tun kp ni nwpn pa Go- mina-agba Qlpla Dokila Mnamidi Azikiwe wipe ki o wa si ni ana pjo Jimp loju gbogbo awpn enia pa- taki palaki lpkunrin ati lobinrin.

Qke-mf ta-o-le-pdggE a-a Jp ponun (£75,000) ni nwpn

fi kp ile gbpagan na, o si gba egbydpgbpn enia, yatp si ile ti alijp, oririsi nkan mere-mere ni nwpn iisi ile tuntun na.

Olpla Dokila KoPowo- rpla Abaypmi ti?e o 1 0 ri awpn olutpju ile na ni o fi kpkprp iyebiyc le Gorni- na- -agba 'na Ipwp ni irpiv ana pe ki 0 fi si ile na.

Page 2: Agan Be Vile Igbimo Asofin : Omo Egbe Alakuko Fake Kori

B'oti -O ftoju ewe Keji Dscamber $ - PguemtV- 14 1962

O gbeni Mado’ u lo la I’a ilan Fun ulove O jikulu :

G N i O k o E r a N i O F e Ko( O be re loju ewe kini ) A w on Lo

tapt. Pullen ala?? oia ni kpbp mejc ati ab? (7 I 2d) r ia ni la'.i ina la iwpn eran kan laisi egun nibe. A ni koie pe wa rara. a n ki 3 la iwpn kan ni kpbp mewa ati abo ( 10 I/2d) la is: egungun. Nigbana ni iwp Oloye Yeki ni Ojikutu wa taramp li Oyinbo na. O gbagoe wipe ppa agbeleka t;hiit loja. O wa ni anlani lati taka’egbp'aw'pn agbal igba. On? na dogun o dpde.

Ni asike na gbogbo is? alapata eran tu u ■ g b a t i gbogbo awpn alapata eran fp di elewon tan. Omp inu )$p tit? paapa ni adajp kan si? si ewpn (u ko fe darukb pkunnn na smu iwe yi) pelt iscase-i.aia. Nigbana iw<? na wa ri ipe nkan ti o nse ko dar«. Lehin eyi ni o wa dide, li o sesi aiva ggb? agbaiagba, awpn bi Ogbeni Madojutpla. Salami I.adp- Um, Olori Adcvemo ni ita Faji, Alhaji.R j - i i iia Faji „ti Athaji Alab; llprin wipe agbalagba ki wa Ipja ki ori

pun? luntun wo, ki nwpn jpwp gba o. ki nwpn li? ba Oyinbo alas? pja yi s<?n? wipe ki o tunofin na $e. Sc cleyi ni iwp Oloye 'jikutu npe ni nWpn wa tuba Cun ■ ??

Oloye Ojikutu kinni o ndun <? ti o tun nsp oko ebu si wa? Awa ki§e amukun tnekp rara; a si kise alaimo- ire. O ri b.- lojti tire ni.

Nitolo a pin eran $ugb?n gbogbi anfani ib? iwp ni o nje. $ebi o tile ni iye eran ti a pin lyjpna lohun ki o to

o ti idpta eran kun lai sp fu • .i.va Janman rara. Nkan ti o li? pgbf rap p lori niyi ni akpkp A I'.- ki o sc irantj nkan li o pa wa pi? ni 1954 A ko ti fy fenu kan iy?n nisisiyi rara

Jamba sole onile taji li o wi ninu prp re Ipse ti o kpja, owe na lir? ni o. A ko fp ki o tun ko wa lo si oko-eru r'keji nr awa Alapata li ki?

? lolori wa, a si fe ki o ko gbogbo eru iwe wa fun wa.

A duro : iiihia, a si nreti 65 re ni osc ti mb? ki a to ■ af-?gba ayanga mg e lori.

A ru fin kun Fe h i Adajjo K olu

llu ‘ Ibu

IKOT-Ekpcne — Gbogbo awpn ero ti b wa si kotn <nvpn plppu ni ilu ti nwpn n p e n i Ikptp-gpcni n i nwijn yanu nigbati nwpn ri O g b e n i E. O. Igboku lise adajp K o l u na, ti o .-.are, ti o fi i? w p f a eti nigbati pdaran kau ti nwpn mu wa si iwaju re fa igu- dan ada yp. ti o nsare bi? wa bo o in? ori ijoko r?.

Onirohin w a ni a w p n plppa ni arufin na ti orukp re nje Sunday Ugbugho ja ­de, nwpn ni ki o wa si? tenu

E SORO NA SOKE!

Alagba’ " J ” S f i *L i k:l J ' , ko H yanju ni 7 Aworan ok: yi ni li i g b a

S Tjr4"'3 Ba,4w»' a,i Ahmadu Bello nfi er? g b o h u o a bJo li iVieiojnone) e: err mbiii aw?n Gtsi pan? i?ja si laipe yi I'Eko.

r? ki adajp to sa konko ntp g. Qrg ejp r? na ni nwpn nro Ipjyp ki o to lit igudan yg, ti o f? Ip bp ori adajp site k i 'adajp na to taju kan an. ti o ri ni o ba'sa wple li o si ti ilpkun mori paiapata.

O to awpn p’opa meiila li n w . n gb- «>gb:ni arufin na mu p-ipanko lenu. pn iv.ira ada|p ki nwpn.. to mu Ip si itimpl

e

iuukis \ p a A w o n Enia Vi flu O vinbe

k iLONDON- Waya irobin fca-i ig wa l(Oyinbo mnu eyili onirohin 'wa N) w (fog) li o bpre ni ijcjc u pa oguulpgp _r.n aii lobmiin, l.ynirvd: lagbi. op -lyp.■'ewe ni nwpn ni laii jnko sile nigbati pkp li nko v.pn |p ko rir.m tarn loju pna.

Awpn ontlu ilu Oyinbo ni awp , n ri iru a»ba- so iKul.ii om-jamba bayi.fo pUun 195?. pam r'ke-

“ ? si ?“ l,i egba.ii (4.000) enia. Nwpu n> awpn ko ti mpiye enitti eleyi na yio pa.

enia ’lokun- awpn pmp- m o i p a i i

A/ILUKA k-ti-Ofe Io si i!e Igbimo awon Asofin P ko, ka irohin soki ti o mo bo wa loju ewe kejo ne yi peiu ;won oro re miran loju ewe karun.

Page 3: Agan Be Vile Igbimo Asofin : Omo Egbe Alakuko Fake Kori

Oju ewe Keta (3) Eleti-Qfce

Alhaji Ju Alhaji Kan Sewon Odun MejiK A J'O - Alhaji Muhammadu Dodo, adajp kctu ilu Kuno da ejp pwpn pdun meji fun Alhaji Shehu Maimola, pga i!c i$e Ijpba Ibil? Kano ti awpn Qippa fi sun psun wipe o gba owo riba 1 p w p pnikan nigba kan.

Ejp li awpn plppa ba pdaran Alhaji ro ni wipe on ni pga ilc is? Ijpba Ibile Kano nibiii nwon ti nyan i§? i u n a w p n kpntrakito, ti r.ba wpn $e alagbusc i.jc. Nwpn ni ki o to gbe i 5 9 f u n Qgbeni kpniirakitp k a n

?jp lire, o ni pro yi ki?e ebi ti on rara, Oba Kano ti ni o fun on la?? wipe ki on gba owo na 1 p w 9 kpntirakitp yi k i awpn fi ra nkan esp sinu ilc Ijpba ti awpn n k 9 fun awpn o$i$e.

ti nwpn npe n i Alhaji Sanni Kwangila, o g b a pdegbenn ppnun ( £700) Ipwp re.

Nigbati pdaran yi r o

Asoju O b a Kano, ti nwpn nra t w a s i Kotu nigbati nwpn nro yjp 11a ni irp ni. O hi Oba Kano ko ra p nkarikm u i p a re rara.

Ijoba Ni Ki OkuWa San Owo-OriCK O — Oku ki in ojv- ■ post ni a ti ngbp ri yagbpit " awpn ala1 -.1 Ijpba Apupp$e ilp wa PEkoni b?kp, nwpn si li to ofii tunttyp kan situ ti nwpn fp ft pwp si ninu ile igbihto awpn a$ofin ti nwpn f? bpre ninU psp yi wipe oku ti o ba ti ku ni lati san owo-ori-

oku 11a wa laiye ti o wa loye ni nwpn ni lati san fun un.

(we ofi n na fenu ba prp awpn nlarcde ti nwpn ba ti kp nra won sile tabi awpn iieraosu pe awpn a ro ti wpn se, §ugbpn nwpn ni lati san owo-ori.

& 'H ft f i A f t A f t f t ft A ftfc

Lagos Saturday December 8 —December 14 1962)

Ayiluka Eleti-Qfp t« o fi oju agba wo ofin owo-ori tuntuu na ti Ijpba fp be re lati ma lo ninu pdun ti nibp ni Ofin na fa kifci, ko si gba?;berp rara fun awpn ti ko e owo-ori san rara.

Iwc ofin na ni awpn bpba- nsinku ni lati san owo-ori enixpni ti o ba ku. Nwpn ni gbogbo eyi ti ko san nigbati

CARSON PAINTS AND VANISHES Bisobu Agba F ad e A g b a k o : Ijo

Haro Ko Sosi S ileILM IO -Gbogbo awpn agba |jp §951 ti nwpn npe

ni Dhrist Church ati awpn pmpwcwp , |jpj§p$i. nu ;ni nwpn binu kp §951 sil? fun Bispbtt— agba E n i-pwp A.W Howell* niton alufa a pn ti o gbc' Kuro Ipdp awirn ni amidi, gbogbo wpn ko si wa ibi isin ikorc

ti nwpn ?c ni §p$i ni ijeje

(Wo yoku loju owe k

Page 4: Agan Be Vile Igbimo Asofin : Omo Egbe Alakuko Fake Kori

Qju ewe Kerin :'4> Eleti-Qf; Lagos Saturday Dice Tiber 8 - P oona’” ' 14 IW>2

ELETI-OFEANJUWQN KO $E WJ L£JQ

EDITORIAL OFFICE & WORKS CABEkS & TELGRAME

2$ Kospkp Street, Lagos. "ELET1—QFE" LAGOS P O. Boj 46S Phona 23370

VOL XIV- No 848, SATURDAY. DEC. 8. - DEC. 14. I96

Iwe Si Qlotu E Wo Se Fun Wa

tunka Awon EniaBi cti ko ba gbp yiakin inu ko ni baje—Owe

awon baba wa ni 1 le Yoruba niyi. ?ugbpn prp na ba 9<V awon al imojuto Ijpba Apappje wa mu lori or? alaye ti Albaji Waziri Ibrahim. Minisita alatnojuto e t o nkan ajc to se lori awpn cnia ti nwgn ti na ka-kiri gbo gbo ile Nigeria ti nwpn k p lati gbe iypri r e jade sita fun gbogbo wa.

Ninu ilc Igbimp a w p :i asofin I'Eko ni ijerin, Minisita r.a so f u n gbogbo agbaiye wipe gbi- gbt- ti awpn ko gbe iypri g b o g b o ti awpn k a tye a wen cnia nasi jade ko nscebiawpn rara biko$e ti awpn aladngbo wa ni Ipinle Ila Orun ni ilu I bo.

Nwpit ni awpn ilu bi Awka, Brass mp agbegbe Ope bo n$e ni nwpr. mbu enia mp enia ti nwpn ka ni’.orina nwpn ci lati tun awpn enia ilu ka ni.

Awa on iwe irohin ‘Eleti— Ofe" lati bi o$u melo kan ti a ti ri wipe prp awpn enia ti nwpn ka na di koko ni a ti me mp gbogbo enyin enia wa leti, odabi enipe awpn kan fe $e aidara nipa re. Awa k o so wipe Ipinle kan ni o jebi pro na. ?ugbpn on a fe fi setigbp yin ni wipe fci e raase prp na ni “ enitt o ba ka mi ka igba iya re," ki e jeki nwpn' ka p tpmp-tpmp ati tokp tpkp.

t \ bosi Leyi!Laipc yi, mgbaii 6bogbo awpn ara ilu Eko f e

Acn 11 ia si lie igbncp minisifa Eko ni a ri ti awon pmp eebc kan ti nwpn npc ni Alaake (NPC) ti Oip’la Amadu Bello. Saidaut.a Soktto cseOlori wpn yan'obin nn ka n jade wipe ki awpn pkunrin ati obinrin dibofun

ki o le wp ile Igbimp.Nkan ti a f ? f i ye enyin pkawe wa nipa o r o

yi ni anlant idibo ti awpn pmp egbe yi kp f u n awpn ob.nnn wpn palp pa la ni Oke Qya nibiu nwpn gbe t i d a e g b p y i stle. Nw n n i obinrin Imale k i sptp si nkan ilu.

Bi o ba je beni. kinni $e ti nwpn fi sp wipe k i awpn obinrin Imale E k . dibo fun awpn tabi OIp- run Imale t Eko yatp. «, Oke Qya y a Medina nitk

Bi prp ko b.. fe dabi prp ala'oosi, akoko to ki a ( awon gbogbo obinnn ilu Oke Qya ni Ipinlp Ariwa ba dek' aW<?n Da em a dlbo “ 'Sbakugba ti asiko lati di

imai^Mn,ni lawi'?n l ra ° k? -̂va y* ko to ti awpn 1 Imale bl t. tlu Urubawa (United Arab Republic). Jon ^ 'n ^ tk u at,.Turke>' rara. sibesibe gbogbo awpn pn wpn obinrin ati ivawo wpn lo njade lati dibo Bi a ba I lati ?e eyi a la bosi ni wa.

C jpwp e b a w a kesi awpn Alamojnto 1 Ijpba Ipio— I? Iwp Orun uti nwpn g b e ofin nla le awpn ti o nfi iSf pulu (Pooh) je is? lori ki nwpn wo prp na sc fun wpn.

Owo li nwpn ni ki nwpn mn wa fi gba ,‘iwc - nse ti pp puppju.WOwo ko s i n i itu tobc mp. »wpn enia ko si ta tfte-bplu to be mp.

Ti a w p n Alamojuto i 5 e ljpba ko ba fe ki a w p n pmp jaguda pp n i I u, ki nwpn ro prp na ?o a.

Eon ni,

A. Alamu

Mushin

•' A .ft A A A A f t & A & f t A «

Eka Irohin AYILUKA NI Oju ewe karun * osose Ati Oro Ologbon Pelu Oye ninu Iwe Eleti-Ofe

YOU WILL NEVER GO WRONGWhen you select and buy any

o f the following100 0/0 WOOL F A N C Y WORSTED SUITINGS

(Made in England)(guaranteed against SUN, AIR & RAIN)

BEST Q U A LIT Y GERM AN VELVET (Various attractive designs & colours)

unbeatable quality & design.H EAVY COTTON GUIPURE ALLOVER

(LACE)

HIGH Q U ALIT Y F A N C Y FURNISHING M ATERIALS

(In Art Silk) various design & colours Price to suit all pockets

H EAVY A R T SILK BROCADE in various colours

(OKUNOW O SPECIAL DESIGN)

ONLY FROMTHE IIOLSE QUALITY &

DURABILITY

63, Massey Street, Faji, Lagos. Telephone: 23114.

Page 5: Agan Be Vile Igbimo Asofin : Omo Egbe Alakuko Fake Kori

Qiu ewe Karun (5~) Eleti-Qfg Lagos Satuiday December 8 —December 14 1962)

Nihin Lohun Ati Nibi Gbogbo

( LATI QWO A Y ILU K A )

Awon “Adele”Ni pse ti o kpja mo sp fun yin wipe awpn ‘•Adele’ ’

alamojuto [59 Ijpba Ipinle 11a Orun (Commission­ers) ti a fi pajasviri yan ti npale mp di? die lati pada si ile wpD nitoripe is? wpn se npari dip dip. pnyin pr9 mi. o yp ki a yin awon ' ‘Adele” wa na nitoripe nwpn se is? kara-kara fun asiko d i p ti nwpn se alamojuto i$e ijpba ipinla na.

Mo mp (Ji? ninu awpnenia mpkandinlogun na ti nwpn yan si ipo "adele” na bi enili o mp owo, mo si mp wipe nwpn ki se pie enia rara. Mo mp a,wpn bi Oloye Jas. Qla. Fagbemi, alamojuto eto il? ati ilu tun- tun; Onipba Adelcke Ademuluyi, alamojuto nkanpgbin ati isura: Qgbpni V. Owolabi gsan, alamojuto eto ina- wo, Qgbpni TEA Saluba. alamojuto eto 9 k p, Oloye S. L. E d u (“ Baba Abiye") alamojuto e t o ilera ati Ogbeni Ade. Thanni ti?e akede Ijpba Ipinle Iwp Orun na.

Ki a wa pada si pdp awon p b a t i nwpn ko gbe wahala is? pataki le lpwp sugbpn ti nwpn w a ni po olubadamptan, awpn bi O b a Akinyple, Olu- badan ati Qba Ibmni, Akcnzua Keji. Mo tile gbp pe Qba Akenzua na sc bpb? ni ilu Asaba laipe yi, 0 fun awpn ara ilu na ni pgprun ppnun fun omi- ?rp ti av/pn ara ilu na fp Fi owo ara wpnLra bi Ijpba ko bi lc ra omi-?rp fun awpn. Mo gbp wip Oloye Osadebcy paapa na se be p?iu. Dennis, o s° pupp ori§a ilu baba r? yio gbe p o.

Alapata D e!Ninu ps? yi iwe mejfc ni mo ri gba lati p 4 o

awpn ti o nka iwe ti ?roo nkp sinu E L E T I-Q f. ni pspsp. Ekinni lati pdp Qgbpni alapata kan. ckef lati pdp olukpni kan ti o pe>a»a r? ni Tisa nipa awpn enia Nigeria ti nwpn fp tun ka(

Enyin ara mi, iwe ti 010 ri gba lati pdp pnrkan ninu awpn pmp ?gbe ‘'alapata eran ilu Elco y i ni mo ti f? junu sugbpn mo wa ri wipe itan fun pj* pla ma mb? ninu ebu nigbaml.an, nitoripe nigbagbo- gbo ni mo ti nma ngbp ti awon orogun lobinrin ti ma bu ara wpn. ti nwpn si nma nsp itan bi bale wpn ti fp pnikan dele si ara wpn.

Iwe ti alapata na kp niyi ; “ Ayiluka t a b i k.i ni o pe ara r? ? O ni Olovc Ojikutu Bi o sp aiye awa alapata dprp lori is? ?ran, Mo f? sp fun p wipe prp ti o ko mp idi r? ni o nda si.

Ase Onikunmo”0 ni Oloye Ojikutu sp aiye awa alapata d p r 9

fun wa. Irp ni eleyi, mo f? fi nkankan ye 9 nipa rp, iycn ni wipe gbogbo bi a ti nsa, ti a nki i, o ko mp wipe gbogbo awa pd pmpde ti a nse is? apart cran lphin Oloye Ojikutu ni a wa, sugbpn gcgpbi O 1 o r i nigbati aiye awa alapata erao i‘Eko le, ti nwpn nko wa da spwpn bi pmp jaguda o dabi pni wipe Oloye na f? jn wa si!?. Ki a sprp si ibiti prp gbe wa, o ju wa silp patapata.

“ Asp-On'rkump paapa nkp ? pnikan ki jp awa de! Nigbati a fi Oloye Ojikutu s« Olori a tun yan awpn Oloye miran pplu r? •: sugbpn gbogbo igba n 1 o mp nyp as? jadeni apo >ara re ti awpn oloye yo- ku ko ni rap rara. Iyc ti nwpn pin ?ran pipa si k 9 ni o wa loni, a si mp enitr o bukun iye pran na.

AYARA-BI-ASA

Aworao yi ni li awpn pmpbinrin ilnj CJpsi mcrin ti nwpn Ip se a}oju i e wpn ninu ere agbaiyc ti nwpn se ni ilu Australia. Onirohio wa ni awpn pmpbinrin nn lc yura sare bi nja.

“ Iwp Ayiluka ni Oloye Ojikutu ti sp aiy- awa alapata pmp Ibadan dcro ati pc gbogbe wa ti a ti j? gbese ni a nrin fSlala ti a nvan. ti a si nkple mple. (?rp yi ko ri bp, olukuluhu ni o mp ibiti bata gbe nta on l?s?. Gbogbo a$p kp ni enia ni lati sa ninu orun. O y? ki Oloye Y?kini Oji­kutu na si fi aye sil? fUn awpn ?!oiniran ki nwvn si lo asiko wpn bi oldri alapata ?ran na ki a wo na.

Emi'ni,Qmp Oke’badan"

“ 9m p Oke’badan” o se pupp pplu alave rp. ko si nkan ti o nlc ti ki rp. boya emi Ayiluka ni ma ba nyin pari ede aiyede yi ki pduii Keresimesi to de.

Atunka EniaIwo keji ti mo ri gba lati pdp “U sa” kan lati

Ikorodu niyi lori awpn enia ti nwpn ni nwpn fp tun ka kakiri ilu Nigeria.

“ Ayiluka, pr6 nyin se lori aw*n enia ti nwpn ti fi igba kan ka ti a ko gbp iye ti nwpn ka wpn si, ati tun gbp wipe nwpn tun ngbero lati tun wa ka. Nibo ni nVvpn ti I> ri own iyc- biye ti nwpn tun fp na lori enia kika na?

"K iloseti awpn a$oju w a 11a f ? lati ma li pbp lo wa bayi? A gbp wipe awpn kan ni Ipinlf kan ni o dabi pnipe nwpn fp bu mp awpn enia ti nwpn ka lpdp ti wpn, oyi lo si jp ki nwpn. gbe iwe ikania na ti sibi kan. E jpwp Ayi- loka, p mas* fi prp na di wa lati o. Emi ni “ Tr?a, 1(k Pj^wa, Tkorodu.”

Page 6: Agan Be Vile Igbimo Asofin : Omo Egbe Alakuko Fake Kori

Oju ewe Kyfa 6i_______ Elcti-Qfe Lagos Saturday December 8 - - DwcanV.- It l ')V

Biscbu-Agba Nfe Iranlowo

Avvoraa oke yi ni ti Ltii-owo Oliver rrcen-Wiikinson, bisobu agba ii Central Africa nibi ipadt kan ti o ti nsoro wipe on fe iranlowo Iati odo awon ojisc Oiorun, on si tun nwa awon enia dudu meji ti nwon y o j e igba keji fun on lati ma se ise Olorun.

Lari bi odun mokania ti bisobu agba yi ti de ile enia dudu wahaia bi yio ti se ri owo ko ile Olorun si ni o mba kiri ni ilu Afirika na.

Ijoba Apapose Ngbero Lati Tun Awon Enia Ka N i Nigeria

EKO-Qrp j'Cbjn y.> a w <j n aiamoiuio Iloba A pa pose tun ngba ero latitun awon enia Ka kakiri gbogbo i!g Nigeria d i p . nlun o>u tueje ti nwpn ko le obc iyori cma Lika

Minwjta alamojuto nkah aje. Alhaji W a 2 omwe irohin tygbati o :n b a w <> n S979 laipe y i n 1 ti Ic g b e iyori awon enia ti nwon k’a na jade.’

(Wo yoku loju ewe8j

ii n w 9 n li ka lati bi i.Ue di ojo oni.

Ibrahim fi eyi ye awon ti o fa a ti a w 9 n k o

(O bore loju ewe kgta)Bisobu A g b a

Miniaita na ui gbogbo idiwo na lati 9 cl 9 awon alamojuto Ijoba Ipinlg IwO Orun ati lla Onm ni o tiwa I la uruiini o; tiwa nitoripe a w o n alamojuto I j o b a Ipinlg Ariwa ni Oke Ari- Qya lohim ti se eto enia Lika ti won ti p.\

Onirohin wa f i y e w a w i p e 11 w 9 n ni lati k o awoi, oigpa wa lati Abg- oku:a rngbati oro n,i fe bi- ge bi adubi tutor! Alufa S. O. Osiyale li nwor, mu Kurd ni Ilaro I9 si Ijgbu Mushm.

A gbo wipe ede uiyedc n a bere lori oro tisa agba kan ti o yawo lodo awon ijo ra moto-ayokele kan fun ona iSg re: awon kan ni Alu­la Osiyale iodi si o r o y i nitoripe ko f§ m a na owo S.si ni inakuna rara.

Awon agbaiagba ti nwon ko fe ki oro na da nkan sile, awon bi Oba Adelina Olubara lali Abeokuta dide si oro na sugbon ko ti loju ra­ra. O ju ggbaji awon enia I9 ti nwon fi aake kori wipe awon ko fe alufa tuntun, Odunuga, ti nwon mu wa fun awon.

Gbogbo awon enia i j 0 So$i Ilaro na si ti kQwc gbo si Bi$obu Olorl gbogbo ijo awon CM S.. Archbishop Patterson wipe ki o ba awon ri si oro na nitoripe Bisobu Howells ko fg mo nkankan rara mpa re, awon fi 9 r 0 na sun titi o ti su awon.

HAVE Y O U exchanged your

O L D WEST A F R IC A N COINS

for Nigerian Money ?

TREE EXCHAN GE at banks e n d s on

December 31st, 1962.

Page 7: Agan Be Vile Igbimo Asofin : Omo Egbe Alakuko Fake Kori

Elcti-QfcO u ewe tCejo Lseos Stitir.l ay December S -December 14

British Colleges W i l l Take M o r e Nigerian Students

LONDON — British universities, colleges,and hos­pitals are ready to take more Nigerian students

in a wide range o f fields o f higher education. That js the cheerful n e w s which Chief Akitoye Coker, Agents-General for Western Nigeria, is hearing du­ring his week's tour o f provincial centres in Britain where Nigerian Students are being trained.

“ I am reall heartened by the Sympathetic response I have received to requests for more places in British,

•colleges a n d universities,’ he told our special corrcs-

| pondent yesterday.

f?; “ We look to Britain to help us in providing higher

: education for our students.; So far 1 am delighted at i'-the response wo1 have ro- I cevicd. " he declared.

H In the first day a n d a half o f his tour the Agent General has already h a d

./promises that the Colleges ■ of Technology and Co- (mmercc in Leeds, York- L-shire, will take more stu­dents. that the Faculty o f '’Medicine at Leeds Univer-

I •

sity will accept a small but regular quota of suitably qualified medical1) students, and that University Depart ments o f Engineering and social Studies will, also con- eider allocating regular pla­ces to Western N i g e r i a Sudents.

There are altcady more than 100 student* from N i­geria in Leeds a n d t h e Agents—General heard ex­cellent reports o f their work.

" The Principal ol t h e Leeds College o f Techno­logy told me l h a t our students h a v e achieved good results and are very enthusiastic: H e said h e would welcome many more

provided o f course- that their qualifications were good This mea s that a<- shall have m •• r e people trained in a variety o f f i­e l d s including printing, science, f o e d technology and dietetics" s u i d Chief Coker

He h a s received siraiiar promises f r o m the Locus College o f Commerce and plans to visit a number o f hospitals in chrdistrict there Nigerian nurses are training.

“ Everywhere 1 shall be e iquiring i n t o the exact standards o f entry into the colleges and universities so

Plushes, Velvet, Vctveleen. Damask

& Building Materials

PLEASE CONSU LT

kunowo Brothers

(63, Massey Street. Faji Market)

that we c.m be cerium o f sending students wli > will cnnvkc.e their c o v r * e i »uccs»sf.i‘ty." he s.iid

Chief C o k e r i s being accompanied by t wt> me- mbei s from ltic Staff £ Their tour will continue in Y o r k, Bradford und Huddersfield, Manchester. Nottingham and Birmin­gham.

Readand

AdvertiseIn

Ekti - Ofe

RT. HON. DUNCAN SANDYS M.P.

. C ,

LAG OS, NIGERIA.

The House Where Courtesy & Satisfacttonc Guaranteed.The Rt If os i D . ,,-un S a n d y s .P C , M.P. Sec­

retary o f .s u , ' , . Commonwealth Relations a n d Secretary ot w or the Colonics, was born on Ja miury 24th I.ds. Ldltca^d a t Eton a n d Magdalen CoHegc, Oxfo, d wuerc he graduated M .A ., he entered the Diplomatic Service tn 1930.

Page 8: Agan Be Vile Igbimo Asofin : Omo Egbe Alakuko Fake Kori

The advanced'•? , . f

quality of the Fiatsixes,,

FIAT 2300 and FIAT 1800 Bmore power, elegance, comfort, disc brakes

I

/ 1

r> \«D s m c -o n % S I > 1 ION WUH3N

DOAN-

■ 40- ' h> I--.. I’P M PlloUU port Pub« b m \ - lilrcet h u m Box liS Ptarnu

2330 SUITOR I Oi-O'fU ) Q L \ QNATADE15, Kosokn Slrcct, Lagos.

JJOU IS00Bjem kx Turin Or Lugos Ex Turin iM). 169!! £1350 C6 38

f'xni l?75 £1,3*0 £710ms

LEVENJIS MOTORS LTD.AGos (I M IBAIJAN RAND KAIH.NA Jl>S fM RT HACOURT ABA.

Mo Ayduka do ilc tgbf- HK1 J»vn ajofui ily wa n i ijurin luii g b <? o r y oflu luniun (■ nwyn IV s0 ni- bf lori awyn ymy vva' t -i nwyn nsc ise ugbejyro ti ? ape ni I y y a (Luwycr) ,7 SUgbon nigbuy mo dc- biB -, W - awyn coia ti nw ynjr1' li isba .un ka (Census) (i nwyr. le gbc nyy isi i f jade nimo ba'Alhaji Wazi- ri Ibrahim, MiaisitR aln- mojuto iso aje, oi o m b a usoju Igbimy na syry lowy Ion gbogbo awyn cnia l i nwyn ka (censusi kakiri ily Nigeria.

He TgbimoQry rg na fe bige b’adu-

bi. niloripc t *̂ o li n>yro na ni ?nym-pjn g j« Sgb '6 a won iky. Ipinte Ijybie tlu- Orun ni Ilu I bo pyn bi c$y- ina, li ara si mu olukulu- l u nibiti nwyn joko .si;; nigbatl nwyn Bril mi, awyn i. iky tali Oke Qya (ilu awyn- • Hausa) ri eteyi, nwyn sarc po awyn ylopa wa pe ho- ya ijaiubyn. le be Ydy. N i- i$$ju afcan, yga Qlypa. ti ft moto-akyru mefa ko awyn ‘ ‘b'ticbajc-kob.ije''. () I y p a wa, mvyn si yi ' ilc Igbimy na ka pclu ibyn lywy wyn.

Akole-ekeAlhaji Waziri IbuthWiil'i

Akylc - ckc (Forgery) |>ylu . ki a ko tkan rnykan p y ninu awyn etu'a ti nwyn ka ninu tie Ijyl.a llaOrun ni ilu Ibo. O ni nwyn $ o cleyi ki nwyn ba Ic mil ri nkan pyitlu ni. A I h ag i Waziri Ibrahim ni yle iiTi Jroju ni o mba awyn alamo- jutoIjybB lpinlv Iwy-Onin ja ni Ibadan. O ni n i n u gbogbo yna niejilelogyta li awyn yan fun veyn w i p e ki nwyn It ka nwyn cnia ipinle wyn, yha m.irun pc- rc ni o yanju nibe.

Awyn Olotu Ijyba na li da lobun wipe ii y ni Alha­ji Waziri pa my awyn ati pe awawi ni gbogbo y r y re na. (yoku di ys? i i mby,