aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/alawiiye tg...

30
1 Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé kta

Upload: others

Post on 20-Jan-2020

8 views

Category:

Documents


0 download

TRANSCRIPT

Page 1: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  1  

Aláwìíyé

Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k∑ta

Page 2: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  2  

Ìt´qka Àkóónú

1 Ìs`qr`q`ngbèsì: Ìt`∑síwájú

2 Ò`nkà Yorùbá ([51 – 100) ŸQkànléláàád´qta dé Qg´qrùn-ún

3 Dídárúkq N`nkan: Ìt`∑síwájú

4 Sísq N`nkan: Ìt`∑síwájú

5 Kíka gbólóhun kéékèèké

6 Kíkq Sílébù

7 Kíkq gbólóhùn kéékèèké

8 Síp´∑lì `qr`q

9 Eré Onítàn

10 Orin qmqdé: Ìt`∑síwájú

11 ŸOwe: Ìt`∑síwájú

12 Àl´q àpam`q

13 Àl´q Onítàn: Ìdí tí imu Ìjàpá fi kù kánúnbó

14 Ìtàn àwqn akqni il`∑ Yorùbá

15 Ìwà rere

16 Àxà bi a xe n

17 Eré qmqdé: Ìt`∑síwájú

18 Ojuxe òbí sí qmq

19 Àwqn ohun-èlò inú ilé

20 ŸQr`q ak´qnil´∑nu

Page 3: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  3  

ŸQr`q ìxìwájú

Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé jáde fún ìwé Yorùbá ilé-∑k´q alák`q´qb`∑r`∑

tí gbogbo wa m`q bí ∑ni mq owó nnì – Aláwìíyé.

A pil`∑ gbé e j´ade ni láti xe ìrànw´q fún omil∑gb∑ àwqn olùk´q tó ´n lo

gbajúgbajà lórí `∑k´q ìk´qni tó sì tún m`q nípa `∑k´q àwqn qmqdé ti bá wa fi ojú

lámèét´q mo ix´∑ náà, w´qn sì gbé òxùbà fún un, kó tóó di pé a gbé e jáde.

A gbìyànjú láti t´q olùk´q s´qnà ni, kò sì sí ohun tó sq pé kí olùk´q, tó bá dá ara

r`∑ lójú má xe xe àfikún sí àwqn ìgbés`∑ tí xe oríxiríxi ìgbéléw`qn kí ó fi dá a lójú

xáká pé kì í xe pé òun ´n yín àgbàdo s´∑yìn igbá nípa kík´q tó ´n k´q àwqn qmq.

Ìrànl´qw´q kan tí a tún xe ni pé a dáhùn `qp`qlqp`q nínú àwqn ìbé`erè `∑k´q

k`q`qkan. A fo dí`∑ nínú àwqn ìbé`erè tí ó j∑ m´q ìwádìí tí a sì f´∑ kí ak´∑k`q´q bá ti ´n

xe ìwádìí yìí, ìm`q yóò tún máa ya lu ara wqn, ìm`q olùk´q pàápàá yóò sì tún

máa gbòòrò sí i.

Ní `qp`q ìgbà, tí w´qn bá ní kí ak´∑k`q´q ó kq àròkq kan tàbí kí w´qn sq àr`qsq

kan, a lè gbé ìlapa èrò kal`∑ láti ran olùk´q l´qw´q. L´∑yìn èyí, ix´∑ olùk´q paraku ló

kù níb`∑.

Tóò, ó tán l´∑nu, ó kù níkùn.

„ máa yáx´∑ o.

Page 4: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  4  

Ÿ„k´q 1

Ìs`qr`q`ngbèsì

Olùk´q níláti k´qk´q xàlàyé ìtàkur`qsq láàrin Àgb∑d∑ àti Dìran p`∑lú Dàp`q.

Kí olùk´q m´∑nuba ìdáhùn tí ó wà fún ìkíni tí àwqn Yorùbá máa ´n lò nídìí ix´∑

qw´q k`q`qkan.

Kí olùk´q xàlàyé bí a xe máa ´n kí alágb`∑d∑ àti ìdáhùn fún ìkíni náà.

Kí olùk´q ka àyqkà ab´∑ `∑k´q yìí sí etígb`q´q àwqn ak´∑k`qq r`∑ nínú kíláàsì.

Olùk´q níláti pe `qkan nínú ak´∑k`q´q r`∑ tó mq èdè Yorùbá kà dáadáa láti bq

síwájú wá ka àyqkà ab´∑ `∑k´q yìí sí etígb`q´q àwqn ∑l∑gb´∑ r`∑ yòókù

Kí olùk´q dárúkq gbogbo àwqn irinx´∑ al´ågb`∑d∑ tí Dìran àti Dàp`q bèèrè nípa

wqn nígbà tí w´qn dé ilé ar´q, àti ìwúlò `qk`q`qkan àwqn irinx´∑ w`qnyei.

Olùk´q níláti xàlàyé ìtum`q àwqn `qr`q w`qnyí fún ak´∑k`q´q pé ‘ilé ar´q’ túm`q sí

ibi-ix´∑ àgb`∑d∑, nígbà tí ‘rák´∑`∑tì’ túm`q sí irin kan gbqqrq tí àwqn qmqdé máa ´n

xí `∑tù orí igi ìxáná sí, tí wqn yóò fi ìxó sí i, tí wqn yóò sì gbá a m´q òkúta tí yóò

sì dún ‘páà’.

Àtúny`∑wò `∑k´q

1 Àbám´∑ta

2 „wìrì

3 J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ sq orúkq tí w´qn ´n pe irin-ix´∑ tí Alágb`∑d∑ fi ´n lu irin.

— qmq owú.

4 J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ sq orúkq tí à ´n pe irin-ix´∑ tí àgb`∑d∑ fi ´n mú irin nínú iná.

— Ÿ„mú.

5 J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ sq bí `awqn Yorùbá xe máa ´n kí alágb`∑d∑, àti pé báwo ni

alágb`∑d∑ náà yóò xe dáhùn.

— Àrqyè o (Ìkíni)

ŸOgún á gbè ´q (Ìdáhùn)

Ix´∑ xíxe

i) J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ xe àpèjúwe ilé-ix∑ àgb`∑d∑ kan tí w´qn ti dé rí. Kí olùk´q rí i

pé ó y∑ ix´∑ wqn wò dáadáa, kí ó xe àtúnxe tó t´q sí ix´∑ wqn.

Page 5: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  5  

ii) J´∑ kí ak´∑k`q´q parí òwe yìí:

— ní qk´q ìkqbè.

iii) J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ fi àmì-ohùn sí orí àwqn `qr`q w`qnyí:

arq — ∑ni tí kò le rìn.

àrq — oríxìí ewì alohùn kan.

àrq — ohun tí a máa ´n fi rq epo.

ar´q — ilé-ix´∑ àgb`∑d∑.

iv) J´∑ kí ak´∑k`q´q yí àwqn gbólóhùn w`qnyí sí `qr`q ∑nu ql´qr`q:

a) Dàp`q sq pé òun kì í xe qmq qba.

b) Túndé sq pé adáj´q ni bàbá òun.

d) Y`qmí sq pé òun ni ak`qwé ∑gb´∑ àwqn.

e) Dèjì sq pé ìyá òun ti di olówó.

∑) Mojí sq pé òun kì í xe òmùg`q.

Ka àkqsíl`∑ ak´∑k`q´q r∑, kí o xe àtúnxe tó y∑ sí i, kí o sì máàkì r`∑ fún wqn.

Page 6: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  6  

Ÿ„k´q 2

Ò`nkà Yor`ubá (51 – 100) ŸQkànléláàád´qta olé qg´qrùn-ún

Kí olùk´q pèsè àwqn n`nkan tí ó xe mú lò fi ka ò`nka yìí b`q láti ilé, ó le j´∑ èso inú

qsàn àgbálùm`q, tàbí ìdérí qtí, kí ó tó wq kíláàsì k´q awqn ak´∑k`q´q.

Kí ol`uk´q sq fún àwqn ak´∑k`q´q r`∑ bákan náà láti mí ìdérí qtí tàbí èso inú

qsàn àgbálùm`q b`q láti ilé kí ó tó di qj´q tí w´qn f´∑ xe ix´∑ lórí ò`nkà yìí.

Kí olùk´q k´qk´q ka àwqn ò`nkà inú `∑k´q yìí fún àwqn ak´∑k`q´q, kí ó sì sq `qnà àti

qgb´qn tí a máa ´n lò láti fi kà á pàápàá jùlq eléyìí tí ó bá lé lórí fíg`q k`q`qkan.

J´∑ kí àwqn ak´∑k`q´q m`q pé:

Qg´qta túm`q sí ogún m´∑ta (20 × 3)

Qg´qrin túm`q sí ogún m´∑rín (20 × 4)

Qg´qrùn-ún túm`q sí ogún márùn-ún (20 × 5)

Ààd´qta túm`q sí ogún m´∑ta dín ∑´∑wàá (20 × 3 – 10)

Àád´qrin túm`q sí ogún m´∑rin dín m´∑wàá (20 × 4 – 10)

Àád´qrùn-ún túm`q sí ogún márùn-ún dín m´∑wàá (20 × 5 – 10)

Àtúny`∑wò `∑k´q

J´∑ kí àwqn ak´∑k`q´q kq àwqn ò`nkà yìí ni fígq.

i) qg´qrin

ii) àád´qrin

iii) `∑rìnl´eg´qrin

iv) aárùn-ún lé láàád´qta

v) qg´qrùn-ún

Ix´∑ xíxe

Kí àwqn ak´∑k`q´q kq `awqn fíg`q yìí sí ò`nkà Yorùbá.

i) 50

ii) 60

iii) 55

iv) 70

v) 90

Page 7: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  7  

Ÿ„k´q 3

Dídárúkq n`nkan: Ìt`∑síwájú

Kí olùk´q béèrè l´qw´q ak´∑k`q´q bí méjì bóyá w´qn ti rin ìlú wqn ká dáadáa. Tó bá

rí b´∑`∑, kí w´qn sq àwqn n`nkan tí w´qn ti rí láàrin ìlú.

Kí ol`uk´q sq `awqn n`nkan tí a lè bá pàdé láàrin ìlú bí qjà, àg´q ql´qpàá, ilé

sinimá, abbl.

Kí olùk´q fi àwòran n`nkan dí`∑ tó wà láàrin ìlú han ak´∑k`q´q.

Àtúny`∑wò `∑k´q

1 Kí olùk´q j´∑ kí ak´∑k`q´q kq àwqn n`nkan tó kq sójú pátáko síl`∑.

Ix´∑ xíxe

1 Kí ak´∑k`q´q kq àwqn n`nkan tí olùk´q k´q wqn síl`∑.

2 Kí ak´∑k`q´q kq n`nkan tí ó bá pàdé láàrin sínú ìwé láti ilé.

3 Kí ak´∑k`q´q sq orúkq àwqn àwòrán tó wà lójú pátákó.

Page 8: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  8  

Ÿ„k´q 4

Ix´∑ qw´q láwùjq Yorùbá\kí olùk´q sq n`nkan tí ix´∑ qw´q j´∑ àti oríxiríxi ix´∑ qw´q tó

wà láwùjq Yorùbá. Ohun èlò fún ix´∑ qw´q k`q`qkan y∑ ní mím`q fún àwqn

ak´∑k`q´q.

Àtúny`∑wò Ÿ„k´q

1 Kí olùk´q ya àwòrán oríxiríxi ohun-èlò àti irúf∑ ix´∑ qw´q tí w´qn ´n lò w´qn

fún.

2 Kí olùk´q sq fún ak´∑k`q´q irúf´∑ ix´∑ qw´q tí qkùnrin àti obìnrin lè xe

Ix´∑ xíxe

1 Kí ak´∑k`q´q dárúkq oríxìí ix´∑ qw´q m´∑rin

2 Kí ak´∑k`q´q sq bí w´qn xe ´n xe ix´∑ qw´q kan tó wù ú

Page 9: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  9  

Ÿ„k´q 5

Kíkà àti kíkq gbólóhùn kéékèèké

Kí olùk´q k´qk´q ka àròf`q ab´∑ `∑k´q yìí sí etígb`q´q ak´∑k`q´q r`∑. J´∑ kí ak´∑k`q´q kan tàbí

méjì náà jáde sí iwájú kíláàsì, láti wá ka ibi keikà ab´∑ `∑k´q yì í bí olùk´q wqn ti

xe kà á sí etígb`q´q wqn.

Olùk´q níláti bèèrè l´qw´q ak´∑k`q´q èyí tó bá rántí xe àwqn n`nkan tí àwqn

m´∑r`∑`∑rin xe nílé wqn, kí w´qn tó máa b`q nílé-∑k´q lónìí láti lè fi ìdí r`∑ múl`∑ pé

ix´∑ inú `∑k´q yìí yé wqn.

Àtúny`∑wò Ÿ„k´q

1 Wùmí

2 Bísí

3 P´ejú

4 J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ kq gbólóhùn m´∑rin àk´qk´q níbi tí w´qn kà sí inú ìwé àjákq

wqn. Kí olùk´q sì y`∑ ´∑ wò, kó ó máàkì r`∑, kí ó sì xe àtúnxe tó y∑.

5 J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ kq gbólóhùn méjì tí ó k´∑yìn nínú `∑k´q náà sínú ìwé àjákq

wqn. Kí olùk´q kà á wò, kí ó tó máàkì r`∑ fún wqn.

Ix´∑ xíxe

i) Kí ak´∑k`q´q tún `qk`q`qkan àwqn `qr`q ìsàl`∑ yìí tò, kí ó sì fi biro xe àtúntò `qr`q

b´∑`∑ sí àfo tí a p`esè sí `∑gb´∑ `qr`q kq`qkan.

a) miK´∑ — K´∑mi

b) júPé — P´ejú

d) yíne — eyín

e) màl`aà — àm`alà

∑) lègè — g`elè

ii) Kí ak´∑k`q´q fi biro kq n`nkan m´∑ta tí Péjú xe nínú `∑k´q yìí sí àfo tí ó w`a ní

ìsàl`∑ yìí.

a) Péjú di irun

b) Péjú wq bùbá

Page 10: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  10  

d) Péjú j∑ `∑kq

J´∑ kí ak∑k`q´q r∑ mq orúkq tí à ´n pe àwqn àw`q w`qnyí ní èdè Yorùbá.

pupa

eérú

ewé

dúdú

Rí i pé o máàkì ix´∑ yìí fún ak´∑k`q´q r∑.

Page 11: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  11  

„k´q 6

kíkq sílébù

kí olùk´q béèrè bí ak´∑k`q´q bá xì rántí ohun tí sílébù j´∑. Ó tún lè sq pé kí wqn fún

sílébù ní oríkì.

Kí olùk´q kq oríxiríxi `qr`q tó ní sílébù kan, méjì àti ql´qp`q sílébù sójú pátákó.

Àtúny`∑wò `∑k´q

1 Kí olùk´q sq fún ak´∑k`q´q kí ó kq `qr`q onísílébù kan sójú pátákó.

2 Kí olùk´q j´∑ kí ak´∑k`q´q ka àwqn `qr`q tí ó kq sójú pátákó.

Ix´∑ xíxe

1 Kí ak´∑k`q´q kq `qr`q ql´qp`q sílébù síl`∑

2 Kí ak´∑k`q´q sq n`nkan ti sílébù j´∑

3 Kí ak´∑k`q´q sq n`nkan tí ó lè j´∑ sílébù kan

Page 12: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  12  

Ÿ„k´q 7

T´qjú ìwà r∑

Kí olùk´q ka ewì inú `∑k´q yìí fún àwqn ak´∑k`q´q, kí ó sì pe ak´∑k`q´q tí ó mq èdè

Yorùbá kà dáadáa láti wa kà á fún gbogbo kíláàsì. Kí olùk´q sq pàtàkì ewì yìí

fún wqn.

J´∑ kí ó yé ak´∑k`q´q pé bí àìsàn bá xe ∑ni tí ó j´∑ ar∑wà púp`q rí, ∑wà ara r`∑ le

bàj´∑, kí ó sì ní àbùkù lára.

Àtúny`∑wò `∑k´q

1 Àìsàn

2 Ìwà

3 Ìwa

4 jìbìtì

5 J´∑ kí ak´∑k`q´q sq irú ènìyàn tí gbogbo ayé máa ´n f´∑. — „ni rere

Ix´∑ xíxe

i) J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ ròyìn `qr´∑ wqn kan tí ó j´∑ qmq rere fún gbogbo kíláàsì.

ii) Kí ak´∑k`q´q fún gbogbo kíláàsì ní orin t`abí ewì kan tí ó j∑ m´q ìwà rere. Xe

àtúnxe sí ibi tí w´qn bá ti xe àxìxe.

iii) Bí ak´∑k`q´q kò bá gbé ohùn sókè t`abí sí ìsàl`∑ rárá lórí `qr`q kan, a kì í

sáábà fi àmì-ohùn sí i lórí.

iv) J´∑ kí ak´∑k`q´q kq irú `qr`q b´∑`∑ márùn-ún mìíràn síl`∑ kí o sì máàkì r`∑ fún

wqn.

v) Nígbà tí ‘oní’ m´q ‘jìbìtì’ ni ó di ‘oníjíbítì’. J´∑ kí w´qn fi ‘oní’ kún `qk`q`qkan

àwqn `qr`q w`qnyí, kí w´qn sì kq àpap`q wqn m´qránm´qrán: pákó, gbèsè,

bàtà, kùm`q, fèrè.

oní + pákó → onípákó

oní + gbese → onígbèsè

oní + bàtà → oníbàtà

oní + kùm`q → oníkùm`q

oní + fèrè → onífèrè

Page 13: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  13  

Ÿ„k´q 8

Àpèkq ∑yq `qr`q àti gbólóhùn

Kí olùk´q j´∑ kí ak´∑k`q´q bíi méjì tàbí m´∑ta b´q sí iwájú kíláàsì láti ka àwqn

gbólóhùn kéékèèké inú `∑k´q yìí sí etígb`q´q wqn.

Olùk´q le ní kí ak´∑k`q´q k`q`qkan máa pe irú gbólóhùn inú `∑kq yìí láti orí wqn.

Olùk´q le ní kí ak´∑k`q´q fa `qr`q-orúkq inú gbólóhùn k`q`qkan jáde. J´∑ kí w´qn fa

`qr`q-ìxe inú gbólóhùn k`q`qkan inú `∑k´q yìí jáde. Kí olùk´q sq ab´∑ ìs`qrí gbólóhùn tí

`qk`q`qkan wqn wà fún ak´∑k`q´q r`∑.

Àtúny`∑wò Ÿ„k´q

1 J´∑ kí olùk´q k´qk´q pe àwqn ∑yq `qr`q inú `∑k´q yìí sí etígb`q´q ak´∑k`q´q r`∑, kí

w´qn sì kq àwqn ∑yq `qr`q náà sínú ìwé àjákq wqn.

2 Kí olùk´q pe àwqn gbólóh`un kúkúrú tí ó t`∑l´∑ ∑yq `qr`q fún ak´∑k`q´q r`∑.

3 Kí olùk´q t´un pe àwqn gbólóhùn m´∑rin tí ó k´∑yìn nínú `∑k´q náà fún

ak´∑k`q´q. Rí i pé o máàkì ix´∑ wqn.

Ix´∑ xíxe

i) J´∑ kí ak´∑k`q´q pa òwe m´ejì tí w´qn bá m`q fún gbogbo kíláàsì. Xe àtúnxe tó

bá y∑ sí ix´∑ wqn, kí ó sì máàkì r`∑ fún wqn.

ii) J´∑ kí ak´∑k`q´q tún `qk`q`qkan àwqn `qr`q w`qnyí tò dáadáa. Kí w´qn sì fi biro kq

èyí tí ó y∑ sí àfo tí ó ti pèsè sí `∑gb´∑ `qr`q k`q`qkan.

a) dùnaláàá — aláaádùn

b) a∑j — ∑ja

d) k`q´∑ – `∑k´q

e) `∑k´∑Àb — Àb`∑k´∑

f) k´qOlù — Olùk´q

Page 14: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  14  

Ÿ„k´q 9

Er´e-onítàn

Ó y∑ kí olùk´q béèrè l´qw´q ak´∑k`q´q bóyá ó ti ka ìwé eré-onít`an rí. Olùk´q lè sq

oríxiríxi ìwé tó j´∑ eré-onítàn

Àtúny`∑wo `∑k´q

1 Kí olùk´q j´∑ kí ak´∑k`q´q ka ìwé éré-onítàn nínú `∑k´q yìí

2 Kí olùk´q béèrè àwqn tó j´∑ `∑dá-ìtàn eré-onítàn náà

3 Kí olùk´q béèrè `∑k´q tí eré-onítàn náà k´q wqn

Ix´∑ xíxe

1 Kí ak´∑k`q´q ka eré-onítàn

2 Kí ak´∑k`q´q sq àk´qlé eré-onítàn náà

Page 15: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  15  

Ÿ„k´q 10

Orin ak´qmqníwà

Kí olùk´q kq àwqn orin inú `∑k´q yìí fún àwqn ak´∑k`q´q, kí àwqn ak´∑k`q´q kq orin yìí

fúnra wqn.

Kí olùk´q pe ak´∑k`q´q bíi méjì tàbi m´∑ta láti kq orin náà fún gbogbo kíláásì.

Àtúny`∑wò `∑k´q

1 Kí olùk´q béèrè l´qw´q `awqn ak´∑k`q´q orin tí ó ´n k´qni ní ìm´qtótó ara nínú

àwqn orin inú `∑k´q yìí.

— orin 1

2 Kí ak´∑k`q´q sq orin tí ó ´n k´q wa ní `qnà tí a kò níí fi xàìsàn.

– orin 3

3 Tún bèèrè orin tó k´q wa láti gbájú m´q ohun tí w´qn ´n k´q wa nílé-∑k´q.

— orin 4 àti 5

4 J´∑ kí àwqn ak´∑k`q´q sq orin tí ó k´q wa pé kò y∑ kí á yájú sí `awqn òbí wa.

– orin 2

Ix´∑ xíxe

i) J´∑ kí àwqn ak´∑k`q´q sq ìdí kan pàtàkì tí kò fi y∑ kí qmqdé m´q ìyá r`∑ lójú.

ii) J´∑ kí àwqn ak´∑k`q´q fi àmì tí ó y∑ sí orí àwqn `qr`q yìí, kí w´qn sì xe àkqsíl`∑

r`∑ sínú ìwé.

Ojo, tutu, axq bata, kokoka, x∑r∑r∑, idanwo, ofo, ∑kq.

Rí i pé o máàkì ix´∑ wqn, kí o sì xe àtúnxe tí ó bá y∑.

Page 16: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  16  

Ÿ„k´q 11

Ipò òwe nínú `edè Yorùbá

Kí olùk´q k´qk´q sq ìtùm`q `owe fún ak´∑k`q´q r`∑.

Kí olùk´q xàlàyé fún ak´∑k`q´q r`∑ àwqn oríxìí `qnà tí à ´n gbà x`∑dá òwe níl`∑

Yorùbá, kí olùk´q dárúkq àwqn `qnà w`qnyí àti àp∑∑r∑ irúf´∑ òwe tí a lè bá pàdé

láb´∑ ìs`qrí k`q`qkan.

Kí olùk´q xàlàyé àwqn `qnà tí à ´n gbà lo àwqn òwe il`∑ Yorùbá àti àp∑∑r∑ fún

ìlò òwe k`q`qkan.

Bí ó til`∑ j´∑ p´e àwqn `qnà tí à ´n gbà fún òwe nítum`q kò sí láb´∑ `∑k´q yìí, síb`∑, ó

y∑ kí olùk´q xàlàyé àwqn oríxìí `qnà tí à ´n gbà fún òwe Yorùbá ní ìtum`q.

Kí olùk´q j´∑ kí `qkan nínú ak´∑k`q´q r`∑ tí ó mq èdè Yorùbá kà dáadáa ka ibi

kíkà inú `∑k´q yìí fún ak´∑k`q´q r`∑.

Àtúny`∑wò `∑k´q

1 Pàtàkì

2 Ìwúrí

3 ya `ql∑

4 „ni tí kò bá ní ìfaradà, tàbí tí kò ní sùúrù

5 J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ pa òwe Yorùbá tí ó le kìl`q fún olófòófó `∑dá.

— òfófó ò gba ∑gbàá, ibi qp´∑ ló mq.

Ix´∑ xíxe

i) J´∑ ki ak´∑k`q´q r∑ pa òwe Yorùbá márùn-ún tí ó m´∑nuba `∑yà ara ènìyan lq.

Ka àkqsíl`∑ ix´∑ ak´∑k`q´q r∑ dáadáa, kí o sì máàkì r`∑.

ii) J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ wá òdìkejì `qk`q`qkan àwqn `qr`q w`qnyí:

rqrùn – nira

àtij´q — òde-òní

dáadáa — búbúrú

d´∑kun — t`∑síwájú

wúwo — fúy´∑

Page 17: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  17  

iii) J´∑ kí ak´∑k`q´q bèèrè b`q láti ilé orúkq `qkan nínú àwqn ewì alohùn ti àwqn

Yorùbá Ÿ„gbá (Ab´∑òkúta). Kí olùk´q y∑ ix´∑ wqn wò, kí ó sì máàkì r`∑ f´un

wqn.

Page 18: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  18  

Ÿ„k´q 12

Àl´q Àpam`q

Kí olùk´q béèrè l´qw´q ak´∑k`q´q bóyá o mq àl´q àpam`q. Tó bá rí b´∑`∑, kí olùk´q

béèrè bóyá ó lè pa àl´q àpam`q.

Àt´uny`∑wò `∑k´q

1 Kí olùk´q pa àl´q àpam`q fún ak´∑k`q´q.

2 Kí ol`uk´q sq fún ak´∑k`q´q kan kí o pa àl´q àpam`q fún àwqn ak∑gb´∑ r`∑.

3 Kí olùk´q kq àl´q àpam`q bí mélòó kan sókè f´un ak´∑k`q´q láti kq síl`∑.

Ix´∑ xíxe

1 Kí ak´∑k`q´q kq àl´q àpam`q wá láti ilé.

2 Kí ak´∑k`q´q kq àl´q àpam`q ojú pátákó síl`∑.

Page 19: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  19  

Ÿ„k´q 13

Ìdí tí imú ìjàpá fi kù kán´nbo

Kí olùk´q k´qk´q sq ìtum`q àl´q tàbí oríkì àl´q fún ak´∑k`q´q r`∑, kí w´qn tó b`∑r`∑ sí í pa

àl´q tó wà nínú `∑k´q yìí.

G´∑g´∑ bí ó xe wà nínú `∑k´q yìí, kí olùk´q b`∑r`∑ sí í pa àl´q àpam`q tó wà nínú

`∑k´q yìí fún ak´∑k`q´q kí olùk´q dúró bí i apàl´q, kí àwqn ak´∑k`q´q j´∑ olùgb´q àl´q.

Kí olùk´q máa pe ak´∑k`q´q láti máa fún àl´q k`q`qkan ní ìdáh`un, eléyìí tí wqn kò

bá gbà ni kí ó x`∑x`∑ sq ìdáhùn àl´q.

Kí olùk´q lo èdè tí a máa ´n lò bí olùgb´q àl´q kò bá gba ìdáhùn àl´q.

Kí olùk´q xàlàyé ìgbés´∑ tí a níláti gbé àti apàl´q, àti olùgb´q àl´q, láti orí ‘Àálq

o’, tí ìdáhùn r`∑ á sì j´∑ ‘ààl`q’.

Olùk´q níláti sq ìtàn `al´q àpagbè inú `∑k´q yìí fún ak´∑k`q´q, láti orí asín, `qk´∑r`∑ àti

ìjàpá.

Kí olùk´q lé orin inú àl´q àpagbè yìí, kí `awqn ak´∑k`q´q r`∑ sì máa gbe orin náà.

Kí olùk´q j´∑ kí àwqn ak´∑k`q´q r`∑ sq qgb´qn àti `∑k´q tí a rí k´q nínú àl´q àpagbè

yìí.

Àtúny`∑wò `∑k´q

1 Ìjàpá àti ŸQk´∑r´∑

2 J´∑ kí ak´∑k`q´q xe àpèj´uwe (i) Eku Asín àti (ii) ŸQk´∑r´∑.

— Eku Asín j´∑ eku oko tí ó dúdú, tí imú àti ∑nu r`∑ gùn xqbqlq, ó máa ´n

ba n`nkan j´∑, ó sì ní oró lára, ó sì máa ´n rùn, nígbà tí ŸQk´∑r´∑ j´∑ ∑ran tí ó ´n

gbé inú igbó, ∑ran jíj∑ ni, irun máa ´n p`q lára àti ìrù r`∑, kì í sì í rùn.

3 J´∑ kí `awqn ak´∑k`q´q r∑ wo àwqn òwe m´∑ta yìí, kí wqn ó sì xe ìwádìí ohun

tí a fi ´n pa w´qn b´∑`∑.

i) Eku kan kì í rùn kí ó borí asín.

ii) Kòkòr`o kan kì í rùn kí ó borí ìkamùdù.

iii) Òbúkq dé, òórùn dé.

Inú ìwé wqn ni kí wqn xe ix´∑ yìí sí, kí olùk´q sì máàkì r`∑ fún wqn.

4 Irun y`∑ù-y`∑ù ni ó bo ara `qk´∑r´∑, ó sì teun ní ìrù tí ó xe y`∑ùy`∑ù, kí ni o m`q

nípa ara àti ìrù ìjàpá àti asín?

Page 20: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  20  

5 J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ xe àlàyé òwe yìí: ‘ŸQlàjà ní í fi orí gba ògbó’. Ka àkqsíl`∑

ak´∑k`q´q r∑… kí o sì xe àtúnxe sí ix´∑ wqn.

Ix∑ xíxe

1 2 3

a) Fi ogun ta kígbe sókè lq ìbòòsí

b) Kán´nbó kín-nkín xínkínní

d) Kùm`q kó´ndó ògbó

e) Fi àáké k´qrí ta kú k`q jál`∑

∑) P`∑l´∑p`∑l´∑ ìbaral`∑ sùúrù

f) Àìfarabal`∑ wàdù-wàdù ìwara-pàpà

Kí olùk´q wo ix´∑ ak´∑k`q´q r`∑ fínnífínní bí a xe xe é sínú àt∑ òkè yìí, kí ò sì xe

àtúnxe tó bá y∑, kí ó sì máàkì ix´∑ wqn.

ii) J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ sq iye ò`nkà w`qnyí ní èdè Yorùbá.

300 — ŸQ´qdúnrún

400 — Irinwó

800 — „gb`∑rin

450 — ŸQtàlénírínwó ó dín m´∑wàá

600 — „gb`∑ta

850 — „gb`∑rinléláàd´qta

500 — Ÿ„´∑d´∑gb`∑ta

95 — Márùn-ún dín l´qg´qrùn-ún

220 — Okòólénígba

650 — Ÿ„´∑d´∑gb`∑rin ó dín àád´qta

Page 21: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  21  

Ÿ„k´q 14

Ìtàn `awqn akqni il`∑ Yorùbá

Kí olùk´q sq ìtumq akqni fún àwqn ak´∑k`q´q. Kí olùk´q b´eèrè bóyá ak´∑k`q´q ti gb

nipa àwqn alágbára ayé àtij´q rí.

Kí olùk´q dárúkq dí`∑ nínú àwqn akqni fún ak´∑k`q´q — Odùduwà, Mqrèmi,

„fúnxetán, Ògèdè`ngbé, abbl.

Àtúny`∑wò `∑k´q

1 Kí olùk´q sq fún ak´∑k`q´q kí ó bé`erè akqni ìlú wqn wá láti ilé.

2 Kí olùk´q kq orúkq àwqn akqni ayé àtiy´q sójú pátákó.

3 Kí olùk´q sq ix´∑ ribiribi tí àwqn akqni ayé àtij´q xe.

Ix´∑ xíxe

1 Kí ak´∑k`q´q kq orúkq akqni márùn-ún síl`∑.

2 Kí ak´∑k`q´q sq ìtàn akqni kan níwájú àwqn ak∑gb´∑ r∑.

Page 22: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  22  

Ÿ„k´q 15

Ìwà rere

Kí olùk´q sq ohun tí èèw`q j´∑ fún àwqn ak´∑k`q´q.

ŸEèw`q ni ohun tí a k`o gbqd`q xe ní il`∑ Yorùbá. Kí ó xàlàyé l´∑kùn-ún r´∑r´∑

èèw`q k`q`qkan àti ìdí tí wqn kò fi gbqd`q xe é. Bí àp∑∑r∑: èèw`q ni kí a pàl´q

láàár`q tàbí `qsán, ìdí tí a kò gbqd`q xe é ni pé a kò ní le mójútó ix´∑ ∑ni.

Èèw`q ni kí a jí rí èèpo `∑gúsí ní àár`q kùtù, `eyí k´q wa pé ká ní ìm´qtótó.

Kí olùk´q sq ìtum`q àwqn `qr`q tí ó bá takókó fún wqn p`∑lú. Bí àp∑∑r∑:

Ìnàjú – ìfixeré tàbí ìfidárayá

Ìrégbè – ìranù

Ma-n-sín-ìn-nì – `∑rq ìrànxq

Àtúny`∑wò `∑k´q

J´∑ kí àwqn ak´∑k`q´q dáhùn àwqn ìbéèrè w`qnyí

i) àár`q

ii) ìnàjú

iii) kí ó má baà fi ìranù x∑w´q

iv) `qsán

1 A kì í fi qw´q gbe òjò

Yorùbá gbàgb´q pé àrá máa sán pa ∑ni náà. Kí òtútù má baà mú ∑ni ná`a

ni w´qn fi sq èyí.

2 Aláboyún kì í rìn lóòrún `qsàngangan.

Yorùbá gbàgb´q pé `alùj`qnú yóò lé qmq inú r`∑ jáde, yóò sì bq sínú

aláboyún náà.

Xùgb´qn nítorí ìlera aláboyún àti qmq inú r`∑ ni w´qn fi sq èyí.

1 J´∑ kí àwqn ak´∑k`q´q wá `qr`q márùn-ún tí ‘q’ parí wqn (Bí àp∑∑r∑ qw´q)

Axq, ab´q, `∑kq, `∑f´q, iy`q

Kí olùk´q máa pe àwqn ak´∑k`q´q ní `qk`q`qkan láti xe èyí.

2 J´∑ kí olùk´q pe àpèkq gbólóhùn méjì tí ó b`∑r`∑ ibi kíkà yìí fún àwqn ak´∑k`q´q

kí w´qn sì kq w´qn sínú ìwé àjákq wqn.

Page 23: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  23  

Kí olùk´q gba ìwé àjákq wqn l´∑yìn ix´∑ wqn, kí ó sì máàkì r`∑.

3 Kí ol`uk´q kq àwqn `qr`q w`qnyí sí ojú pátákó

i) Opo (wàhálà)

ii) Opo (Igi tí a fi k´ql´q)

iii) Opo (obìnrin tí qkq r`∑ kú)

L´∑yìn `eyí, kí olùk´q sq ìtum`q `qk`q`qkan fún àwqn ak´∑k`q´q láti le j´∑ kí w´qn fi

àmì sí orí `qk`q`qkan wqn.

Òpò, Òpó, Opó

Page 24: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  24  

Ÿ„k´q 16

Òfin tó de oúnj∑

Kí olùk´q béèré irúf´∑ oúnj∑ tí àwqn ak´∑k`q´q j∑ wá láti ilé àti irúf´∑ oúnj∑ tí w´qn

f´∑ràn jù.

Kí olùk´q sq fún àwqn ak´∑k`q´q bí w´qn xe ´n pèsè oríxìí oúnj∑ bí m´∑ta.

Àtúny`∑wò `∑k´q

1 Kí olùk´q kq oríxiríxi oúnj∑ Yorùbá sójú pátákó.

2 Kí olùk´q xàlàyé bí w´qn xe ´n wá oúnj∑ k`q`qkan tó wà lójú pátákó.

3 Kí olùk´q sq fún ak´∑k`q´q kí ó kq oúnj∑ tó wà lójú p´atákó sínú ìwé.

Ix´∑ xíxe

1 Kí ak´∑k`q´q sq oríxìí oúnj∑ márùn-ún síl`∑.

2 Kí ak´∑k`q´q gbìyànjú láti xe oríxìí oúnj∑ méjì nílé.

Page 25: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  25  

Ÿ„k´q 17

Eré qmqdé

Ó y∑ kí olùk´q béèrè bóyá àwqn ak´∑k`q´q ´n xeré ìdárayá nílé. Kí olùk´q sq fún

ak´∑k`q´q oríxiríxi eré qmqdé tó wà – bojú bojú, ∑kùn m´∑ran, ∑ má w`∑yìn, abbl,

kí ó sì sq ewù tó wà nínú àwqn eré w`qnyí.

Àtúny∑wò `∑k´q

1 Kí olùk´q sq bí wqn xe ´n xeré qmqdé k`q`qkan fún ak´∑k`q´q.

2 Kí olùk´q sq fún ak´∑k`q´q kí ó kq eré qmqdé ojú pátákó síl`∑.

Ix´∑ xíxe

1 Kí ak´∑k`q´q xe ere qmqd´e kan nínú kíláàsì

2 Kí ak´∑k`q´q k´q eré qmqdé m´∑ta wá láti ilé

Page 26: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  26  

Ÿ„k´q 18

Ojúxe òbei sí qmq

Kí olùk´q xàlàyé ètò agbo-ilé bí ó xe wà láyé àtij´q àti ní ayé `ode-òní fún

ak´∑k`q´q.

Kí olùk´q fi yé ak´∑k`q´q r`∑ ∑ni tí ó máa ´n j∑ olórí agbo-ilé níl`∑ Yorùbá ní àtij´q

àti àwqn tí w´qn wà láb´∑ àk´oso r`∑.

J´∑ kí ó yé ak´∑k`q´q r∑ pé l´∑yìn bale ilé, ∑ni tó j´∑ qkq ni àwqn ìyàwó r`∑ tí èyí tí

ó k´qk´q f´∑ j´∑ ìyaálé, kí ètò tó kan àwqn qmq wqn.

J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ mq bí ìdílé kan xe é k´q ilé wqn láyé àtij´q, àti bí w´qn xe ´n k´q

ilé ní ìdílé k`q`qkan láyé òde-òní.

Kí olùk´q xàlàyé xàlàyé ix´∑ àwqn qmq k`q`qkan nínú ìdílé il`∑ Yorùbá láyé àtij´q

àti lóde-òní p`∑lú.

Àt´uny´∑wó `∑k´q

1 méjì

2 m´∑ta

3 qmq

4 Agbo-ilé ŸQk´∑

5 qmq bíi m´∑rin

6 Baálé ilé tí ó j´∑ qkq wqn

Ix´∑ xíxe

i) J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ ròyìn bí agbo-ilé w´qn xe rí fún olùk´q.

ii) J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ pa `owe méjì tí ó bá `qr`q agbo-ilé lq. Kí olùk´q rí i pé ó ka

àkqsíl`∑ wqn, kí ó tó máàkì r`∑.

iii) Kí `qr´∑ ak´∑k`q´q r∑ pe àpèkq gbólóhùn méjì tí ó b`∑r`∑ `∑k´q yìí fún wqn, kei

w´qn sì kq w´qn síl`∑. Y∑ àkqsíl`∑ wqn wò dáadáa, kí o tó máàkì r`∑ fún wqn.

iv) B`eèrè l´qw´q ak´∑k`q´q r∑ bóyá w´qn mq oríkì-oríl`∑ wqn. J´∑ kí wqn kq

gbólóhùn már`un-ún síl`∑ nínú oríkì ná`a.

v) J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ fi bírò kq méjì nínú àwqn àìsàn tí ó le xe ∑ní bá ´n mu omi

tí ó d`qtí sí ìsàl`∑ tí àfo wà nínú ìwé wqn.

Page 27: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  27  

vi) J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ tún àwqn `qr`q w`qnyí kq dáadáa sí àwqn àfo tí ó wà ní

`∑gb´∑.

a) kqwéalá — alák`qwé

b) Àk´qpoyí — Àk´qyípo

d) ŸQkank`q`q — ŸQk`q`qkan

e) ò`orèrèkóò — òòrèkóòrè

∑) áfíààlà — àlààfíà

f) márúnràà — márààrún

Page 28: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  28  

Ÿ„k´q 19

Àwqn ohun-èlò inu ilé

Kí olùk´q béèrè l´qw´q ak´∑k`q´q bí o bá mq dí`∑ nínú àwqn ohun-èlò tó lè bá pàdé

nínú ilé.

Kí ak´∑k`q´q m´∑nuba `qp`qlqp`q ohun-èlò inú ilé àti ìwúlò wqn.

Àtúny`∑wò ∑kq

1 Kí olùk´q sq fún ak´∑k`q´q kí ó kq àwqn ohun-èlò inú ilé síl`∑.

2 Kí olùk´q sq fún ak´∑k`q´q ibi tí a ti lè bá ohun-èlò k`q`qkan pàdé nínú ilé.

Ix´∑ xíxe

1 Kí ak´∑k`q´q kq ohun-èlò tí olùk´q kq sójú pátákó síl`∑.

2 Kí ak´∑k`q´q dárúkq ohun-èlò inú ilé márùn-ún.

Page 29: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  29  

Ÿ„k´q 20

ŸQr`q ak´qnil´∑nu

Kí olùk´q ka `qr`q ak´qnil´∑nu ab´∑ `∑k´q yìí sí etígb`q´q r`∑. Kí ó kà á tó `∑`∑mejì fún

wqn, nítorí kí ó baà lè yé wqn dáadáa.

Kí olùk´q pe `qkan nínú ak´∑k`q´q r`∑ láti kà á bí olùk´q wqn xe kà á sí etígb`q´q

àwqn ∑l∑gb´∑ wqn yòókù nínú kíláàsì.

Olùk´q lè bèèrè ak´∑k`q´q tí ó bá mq `qr`q ak´qnil´∑nu báyìí tí ó yàt`q sí ti inú `∑k´q

yìí láti wá kà á sí etígb`q´q àwqn ∑l∑gb´∑ r`∑ yòókù nínú kíláàsì.

Àtúny`∑wò `∑k´q

1 gb´qfá gb´qfà

2 qfà

3 `∑pa

4 J´∑ kí ak´∑k`q´q sq ohun tí Alápà tó j`∑pa kò gbqd`q xe.

— kò gbqd`q dé Àpápá.

5 Alápà tó j`∑pa

Ix´∑ xíxe

i) J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ kq gbólóhùn ewì méjì nínú èyí tí `qr`q tó bá ní ‘rin’ nínú

yóò ti p`q.

Rí i pé o y∑ ix´∑ ak´∑k`q´q r∑ wo dáadáa, kí o sì xe àtúnxe tí ó bá y∑ sí i.

ii) J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ sáré pe `qk`q`qkan àwqn gbólóhùn w`qnyí l´∑`∑mejì láìsi

`qkankan pè níb`∑.

a) Òrìxà j´∑ n là, má j`∑´∑ n kú.

Òrìxà má j`∑´∑ n kú, j´∑ n là.

b) Èèrí ará Ìlqràá l∑ran ará Ìlqràá ´n j∑.

iii) Kí olùk´q pe àpèkq gbólóhùn m´∑rin àk´qk´q nínú `∑k´q yìí fún ak´∑k`q´q kí w´qn

sì kq w´qn síl`∑.

iv) J´∑ kí ak´∑k`q´q r∑ wá àwqn gbólóhùn méjì tí ó ní `qr`q ak´qnil´∑nu bíi ti inú `∑k´q

yìí b`q láti ilé, kí olùk´q y∑ ix´∑ wqn wò bí w´qn bá ti mú un dé, kí ó sì máàkì

r`∑ fún wqn.

Page 30: Aláwìíyé Ìwé ìt´qnis´qnà olùk´q ìwé k taapi.volunteer.npvn.ng/media/pdfs/Alawiiye TG 3.pdf! 3! ŸQr`q ìxìwájú Eléyìí ni ìwé ìt´qnis´qnà Olùk´q tí a gbé

  30  

v) J´∑ kí ak´∑k`q´q fi `qr`q tí ó bá `qk`q`qkan àwqn àlàfo inú àwqn gbólóhùn w`qnyí

mu dí ib`∑.

a) ìgbá

b) òjó

d) orín

e) ikún

∑) òro