intlsos ebola poster 07oct2014 v1 yoruba...ebola • kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn kan ni ó...

Post on 07-Mar-2020

1 Views

Category:

Documents

0 Downloads

Preview:

Click to see full reader

TRANSCRIPT

   EBOLA• Kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn kan ni ó má a n fa

Ebola.

• Kò sí àjẹsára, kò sí ìwòsàn kankan – ṢÙGBỌ́N gbígba ìtọ́jú ní àwọn Ibùdó Ebola LÁSÌKÒ a má a mú ànfàní àti lè rí ìmúláradá pọ̀ síi

• A má a fa àìsàn tó rorò púpọ̀, pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ sísun

• Ó jẹ́ àrùn tó má a n tètè ran ni; ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ló lè kó àrùn náà ní kíákíá

• Ènìyàn tó pọ̀ tó aadọrun nínú ọgọrun (90%) ni yóò kú

• Àwọn ẹnití ó ní àrùn náà lè kó o ran àwọn ẹlòmíràn

Òkú pàápàá lè tan àrùn náà káàkiri. Ṣọ́RA (Kíyèsára ní sísin òkú. Máṣe súnmọ́ ọ)

• MÁṢE fọ̀, fọwọ́kàn tàbí fi ẹnu ko ara òkú

• MÁṢE fọ ọwọ́ nínú garawa tàbí korobá kan náà pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn tó ti fọwọ́kan òkú náà

KÍ NI Ó JẸ"?

SYMPTOMSLè bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kejì sí ọjọ́ kọkànlélógún (2-21) lẹ́yìn tí ènìyàn bá ṣe alábàápàdé ẹnití ó ti ní àìsàn náà tàbí pẹ̀lú ara rẹ̀

ÀWỌN ÀMÌ ÀKỌ"KỌ" ÀÌSÀN NÁÀ ÀWỌN ÀMÌ ÀÌSÀN NÁÀ MÌÍRÀN NÍGBÀTÍ Ó BÁ PẸ"

IBÀ INÚ RÍRU ORÍ FÍFỌ́ ÌRẸRA ÈÉBÌ ÌGBẸ́ GBUURU IKỌ́ Ẹ̀JẸ̀ SÍSUN

LÈ KÓ EBOLA LÁTI ARA ẸNITÍ N ṢÀÌSÀN TÀBÍ ẸNITÍ Ó TI KÚ

MÁ A FỌ ỌWỌ́ RẸ NÍGBÀ GBOGBO - Lo ỌṢẸ (Bí o kò bá lè fọ̀ ọ́, lo ìpara tó ní ọtí-líle nínú)

Máṣe fọwọ́kan àwọn ẹnití ó ní àrùn náà tàbí omi ara wọn Ẹ̀JẸ̀, ÈÉBÌ, ÌGBẸ́ TÀBÍ ÌGBẸ́ GBUURU, ÌTỌ̀

EBOLA wà lára àwọn ẹranko àti àdán náà. MÁṢE fọwọ́kan “ẹran ìgbẹ́” tàbí àdán, má sì ṣe jẹ wọ́n

• Pe ilé-ìwòsàn rẹ, kí o sì sọ fún wọn nípa àìsàn rẹ

• Fetísí ìmọ̀ràn. A lè ní kí o lọ sí iléìwòsàn pàtàkì kan

• Máṣe súnmọ́ àwọn ẹlòmíràn kí àwọn náà má bá bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣàìsàn

• Ṣọ́ra púpọ̀ fún èébì àti ìgbẹ́ gbuuru rẹ

ÌDÈNÀ ÀRÙN

A ṣe àgbékalẹ̀ àlàyé yìí fún èrèdí ẹ̀kọ́ nìkan, ó sì jẹ́ òtítọ́ ní àsìkò tí a ṣe àgbéjáde rẹ̀. Kìí ṣe pàṣípààrọ̀ fún ìmọ̀ràn láti ọwọ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ òṣìṣẹ́ ìlera rárá. Bí o.bá ní ìbéèrè tàbí àníyàn Kankan nípa kókó-ọ̀rọ̀ yòówù tí a ṣe àlàyé rẹ̀, jọ̀wọ́ kàn sí akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ òṣìṣẹ́ ìlera rẹ.kiafya.

© 2014 AEA International Holdings Pte. Ltd. All rights reserved. Unauthorised copy or distribution prohibited. 07 October 2014 YORUBA For more information: www.internationalsos.com/ebola

Lè ní ẹ̀jẹ̀ nínú

(láti imú, ẹnu, awọ-ara)

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kò sí ìwòsàn, gbígba ìtọ́jú ní àwọn Ibùdó Ebola LÁSÌKÒ a má a mú ànfàní

àti lè rí ìmúláradá pọ̀ síi.

BÁWO NI Ó ṢE LÈ RAN ẸLÒMÍRÀN?

Lè ní ẹ̀jẹ̀ nínú Lè ní ẹ̀jẹ̀ nínú

OHUN TÍ O LÈ ṢE bí o bá n ṣàìsàn

Àwọn ẹnití ó wà pẹ̀lú aláìsàn náà ni ó wà lábẹ́ ewu tó pọ̀ jù:

Àwọn ẹbí Àwọn òṣìṣẹ́ ìlera

top related