ÌbÉÈrÈ fÚn Àti ÌfikÚn lÁti fi fÁÌlÌ lÉlÈ fÚn ÀṢẸ ÀtÚ ̣e ... · tó bá ku...

15
ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLẸ̀ FÚN ÀṢẸ ÀTÚNṢ E ÌDÁÀBÒBÒ ÒFIN NÍ ILÉ Ẹ̣ Ẹ KÙN NÍ CYPRUS ÌTỌ́NISỌ́NÀ Jò ̣wó ̣ Kó ̣kó ̣ Kà Á 1. Kọ́kọ́ parí fífi ìròyìn sílè ̣ lórí fọ́ọ̀mù Ìfikún. Kì í e dandan kí o dáhùn gbogbo àwn ìbéèrè. Bó tilè ̣ jé ̣ wí pé ó e kókó kí o falà sí (àwn) àpótí tí yóò àlàyé dáadáa fún Ilé jọ́ ìdí wnyi lati fi ti ibeere fun ìdáàbòbò ni kiakia láti dá Ilé jọ́ dúró láti fún ni à ìdáàbòbò láti dá ni tí a pè lé ̣jọ́ dúró láti kàn sí . 2. Dáhùn Fọ́ọ̀mù 45. L sí ìfikún r, bí àpr, “"Wo Ìfikún Olùfisùn Tí a Som". Ẹ̀dà fọ́ọ̀mù 45 tó jẹ́ òfìfo wà nílẹ̀ láti k ìròyìn r sí. 3. Parí Fọ́ọ̀mù Ìbúra. L sí ìfikún r, bí àpr, "Wo Ìfikún Olùfisùn Tí a Som". Ẹ̀dà fọ́ọ̀mù ìbúra wà nílẹ̀ fún láti k ìròyìn r sí. 4. Parí fọ́ọ̀mù Ìwé Òfin (O.2, R.1). Ẹ̀dà fọ́ọ̀mù náà wà nílè ̣ fún láti fi ìròyìn r si. 5. Tó bá ku díẹ̀ káàtó fún , jọ̀wọ́ ri pé o párí Fọ́ọ̀mù tó y (O.8, R.1). Àwn ẹ̀dà òfìfo wà nínú ìdì fọ́ọ̀mù yìí. 6. ẹ̀dà àkọ́lẹ̀ r tí a ti fwọ́sí pẹ̀lú déètì àti àwn fọ́ọ̀mù tí o ti fi ìròyìn r sí láti fún lọ́pàá kó lè fi fún ni tí a pè lé ̣jọ́, kó sì fi wọ́n pamọ́. Kó sì so À mìíràn ti Ilé jọ́ lè fún m. 7. O gbọ́dọ̀ mú ojúlówó àwn ẹ̀dà àkọ́lẹ̀ tó wà lókè yìí tí o ti parí pẹ̀lú déètì, ti a sì ti fwọ́sí l sí Ilé jọ́ kùn agbègbè r fúnra r. 8. A lè ní kí o san owó fún Fífi jọ́ Lọ́lẹ̀ Ní Ilé jọ́ fún Ìbéèrè Fún Ìdúró Fún R. 9. Tí a bá k Ìbéèrè fún, fún ìdúró fún r, O lè fi pe jọ́ kò-tẹ́-mi-lọ́rùn. A ó pèsè fọ́ọ̀mù ilé jọ́ ò-té ̣-mi-lọ́rùn fún , pè ̣lú fọ́ọ̀mù Ìfi Lé ̣tà Jíé ̣. O lè bèrè lọ́wọ́ Ilé jọ́ ìgbà tí àkókò r láti bèrè fún jọ́ kò-té ̣-mi-lọ́rùn máa dópin.

Upload: hoangkhuong

Post on 10-Apr-2018

228 views

Category:

Documents


9 download

TRANSCRIPT

Page 1: ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLÈ FÚN ÀṢẸ ÀTÚ ̣E ... · Tó bá ku díè ̣káàtó fún ӑ, jòẉó ̣ri pé o párí Fóọ̀ṃù tó yӑ (O.8, R.1)

ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLÈ FÚN ÀS E

ÀTÚNS E ÌDÁÀBÒBÒ ÒFIN NÍ ILÉ E JÓ E KÙN NÍ CYPRUS

ÌTÓNISÓNÀ

Jòwó Kókó Kà Á

1. Kókó parí fífi ìròyìn sílè lórí fóòmù Ìfikún.

Kì í se dandan kí o dáhùn gbogbo àwon ìbéèrè. Bó tilè jé wí pé ó se kókó kí o falà sí

(àwon) àpótí tí yóò sàlàyé dáadáa fún Ilé Ejó ìdí wonyi lati fi ti ibeere fun ìdáàbòbò

ni kiakia láti dá Ilé Ejó dúró láti fún e ni àse ìdáàbòbò láti dá eni tí a pè léjó dúró láti

kàn sí e.

2. Dáhùn Fóòmù 45. Lo sí ìfikún re, bí àpeere, “"Wo Ìfikún Olùfisùn Tí a Somo".

Èdà fóòmù 45 tó jé òfìfo wà nílè láti ko ìròyìn re sí.

3. Parí Fóòmù Ìbúra. Lo sí ìfikún re, bí àpeere, "Wo Ìfikún Olùfisùn Tí a Somo".

Èdà fóòmù ìbúra wà nílè fún e láti ko ìròyìn re sí.

4. Parí fóòmù Ìwé Òfin (O.2, R.1). Èdà fóòmù náà wà nílè fún e láti fi ìròyìn re si.

5. Tó bá ku díè káàtó fún e, jòwó ri pé o párí Fóòmù tó ye (O.8, R.1). Àwon èdà òfìfo

wà nínú ìdì fóòmù yìí.

6. Sèdà àkoólè re tí a ti fowósí pèlú déètì àti àwon fóòmù tí o ti fi ìròyìn re sí láti

fún olópàá kó lè fi fún eni tí a pè léjó, kó sì fi wón pamó. Kó sì so Àse mìíràn ti

Ilé Ejó lè fún e mo.

7. O gbódò mú ojúlówó àwon èdà àkoólè tó wà lókè yìí tí o ti parí pèlú déètì, ti a

sì ti fowósí lo sí Ilé Ejó Ekùn agbègbè re fúnra re.

8. A lè ní kí o san owó fún Fífi Ejó Lólè Ní Ilé Ejó fún Ìbéèrè Fún Ìdúró Fún Re.

9. Tí a bá ko Ìbéèrè fún, fún ìdúró fún re, O lè fi pe ejó kò-té-mi-lórùn. A ó pèsè

fóòmù ilé ejó ò-té-mi-lórùn fún e, pèlú fóòmù Ìfi Létà Jísé. O lè bèrè lówó Ilé

Ejó ìgbà tí àkókò re láti bèrè fún ejó kò-té-mi-lórùn máa dópin.

Page 2: ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLÈ FÚN ÀṢẸ ÀTÚ ̣E ... · Tó bá ku díè ̣káàtó fún ӑ, jòẉó ̣ri pé o párí Fóọ̀ṃù tó yӑ (O.8, R.1)

Kí ni ÀSE ÌBÉÈRÈ FÚN ÌDÁÀBÒBÒ PÀJÁWÌRÌ ÌDÚRÓ FÚN NI? Ìdúró fún ni túmò sí kí Eni tí a pè léjó tàbí agbejórò rè má sí ní ilé nígbà ìgbéjó, tàbí kí á

fun ní ìwé nítorí ohun pàjáwìrì tó selè lórí èsùn tó wà nílè.

Pàjáwìrì túmò sí ohun tó n selè lówólówó.

Àse Ìdáàbòbò túmò sí pé a dá ààbò bo olùfisùn lówó Eni tí a pè léjó.

Àse Ilé Ejó jé àwon àtúnse tí Ilé Ejó sèdá, níbi tí olùfisùn kò bèrè fún owó fún àdánù

rè, sùgbón ó n bèrè fún àtúnse tí yóò dékun ohun kan tàbí òmíràn láti wáyé.

Ohun Tí Kò Kàn Wá:

Tí o bá fé dúró fún ara re láti bèrè ìgbéjó ní Ekùn Ilé Ejó ní Cyprus fún Àse

Ìdáàbòbò Pàjáwìrì Ìdúró fún ni láti lè dá (àwon) eni tí a pè léjó dúró, kí wón má bà

á kàn sí e. A pèsè àwon fóòmù àti ìtónisónà wònyí gégé bí ìtóni fún e láti lè fi ran

ara re lówó. Kí wón má sì lò ó gégé bí ìmòràn fún òfin tàbi kí o ri gégé bí ohun tó

sojú ètò òfin.

Page 3: ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLÈ FÚN ÀṢẸ ÀTÚ ̣E ... · Tó bá ku díè ̣káàtó fún ӑ, jòẉó ̣ri pé o párí Fóọ̀ṃù tó yӑ (O.8, R.1)

ÌBÚRA

Èmi,……………………………………………………………………………………

……. láti ………………………………………………………… tó jé eni tó ní Òrò-

àsírí/Káàdì Àlejò/Káàdì Ìdánimò pèlú Nónbà.………………………………. ....

Mo búra, mo sì so àwon nnkan wònyí:

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

………………………………………………………………………………………….

ENI BÚRA NÁÀ

………..………..………….……………

Tí búra, Ó sì tí fowósí i níwájú mi

sí Ekùn ilé ejó ti ……………………..

lónìí …………………………………..

AKÒWÉ ÀGBÀ ILÉ EJÓ

Page 4: ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLÈ FÚN ÀṢẸ ÀTÚ ̣E ... · Tó bá ku díè ̣káàtó fún ӑ, jòẉó ̣ri pé o párí Fóọ̀ṃù tó yӑ (O.8, R.1)

Ìfikún

Fóòmù 45

Ìbéèrè Fún Ìdúró Fún Ni

Fún Ìtura Àse Pàjáwìrì

DÉÈTÌ:

ÀKÓKÒ:

OLÙFISÙN

Orúko Ìdílé:

Orúko àkókó:

Orílè-èdè:

Ojó Ìbí:

Àdírèsì:

Fóònù:

Ímeèlì:

Ìlú:

SO ÀWON ÌDÍ TÍ O FI SE ÌBÉÈRÈ FÚN ÌDÚRÓ FÚN NI. SO ÀWON OHUN ÌTURA TÍ O FÉ KÍ ILÉ EJÓ SE FÚN E

BÉÈNI

BÉÈKÓ

ÌSÈLÈ ÀÁRÍN EBÍ

Àwon ènìyàn tí wón n gbé ní Ile Olùfisùn

Orúko àti Orúko Ìdílé : Ojó Ìbí : Àjosepò Tó wà Láàrin Ebí :

1

1

2

3

4

5

6

ENI TÍ A PÈ LÉJÓ

Orúko Ìdílé : Orúko :

Ojó Ìbí : Orílè-èdè :

Àdírèsì

Fóònù

Page 5: ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLÈ FÚN ÀṢẸ ÀTÚ ̣E ... · Tó bá ku díè ̣káàtó fún ӑ, jòẉó ̣ri pé o párí Fóọ̀ṃù tó yӑ (O.8, R.1)

1. Njé omo orílè-èdè Cyprus ni Olùfisùn, tó sì jé omo Orílè-èdè Egbé Europe?

2. Njé ó wun Olùfisùn láti Béèrè Fún Ìdúró Fún Ni fún àse ìdáàbòbò pàjáwàrì pé kí ó má sí ajosepo kankan pèlú Eni tí a pè léjó. Nítorí pé Olùfisùn ní ìdí tó yè koro, kí Eni tí a pè léjó ma bà á wá kànsí tí a bá wo àwon ìdí tó wà nínú ìfikún. Èyí sì fihàn wí pé Eni tí a pè léjó tàpá sí ètó Olùfisùn nínú ètó Cyprus àti ti Omo Egbé EU sí ètó omo ènìyàn tí à n sòrò rè yìí?

3. Sé lóòótó ni Olùfisùn fé lábé òfin àti lábé irú ìbéèrè fún ìdúró fún ni tó wí pé sé ó se kókó kí olùfisùn dúró fúnra rè láti lè gba ààyè sílé ejó fún ààbò pàjáwìrì?

4. Njé Olùfisùn sàtòjo àwon ìdí wònyí nísàlè gégé bí àtìléyìn fún Olùfisùn pé kí ilé ejó lè fún e ní àse ìdúró fún ni gégé bí òfin se ti so?

5. Sé lóòtó ni pé o kò fé ìkànsí Eni tí a pè léjó nítorí pé ó n dérùbá, ó sì n

dáyàfò ó tàbí ó n halè mó e, ní èyí tó lòdì sí ètó re láti jègbádùn ilé ayé

re? 1

6. Sé lóòtó ni pé o kò fé kí Eni tí a pè léjó kàn sí e, nítorí pé ó jé ohun tó n

tako òmìnira àti ààbò re? 2

7. Sé lóòtó ni pé o kò fé kí Eni tí a pè léjó kàn sí e, a si gbódò ka lówókò

láti dáàbò bo ara re àti/tàbí àwon omo re kúrò lówó ewu tàbí ìfarapa tó

lè selè? 3

8. Sé lóòtó ni pé ó máa dúró fún ara re se kókó láti lè gba àse ní kíákíá láti

lè ká Eni tí a pè léjó lówókò kó má bà á ní ààyè sí e, látì lè dènà ewu

tàbí ìjànbá sí e tàbí sí àwon omo re tí o kò bá lè dúró de ìrànlówó òfin

tàbí tí o kò bá ní owó láti gba agbejórò? 4

9. Sé lóòótó ni pé o kò fé kí Eni tí a pè léjó kàn sí e nítorí pé o gbàgbó wí

pé ó n di ètó ìdáwà re lówó? 5

10. Sé lóòótó ni pé o kò fé kí Eni tí a pè léjó kàn sí e nítorí pé ... kò fàyè gbà

é láti fi èrò okàn tàbí ìmòràn re hàn síta gbangba? 6

11. Sé lóòótó ni pé o kò fé kí Eni tí a pè léjó kàn sí e nítorí pé ó n dí ètó re

lówó láti yan (àwon) egbé tó wùn é pèlú elòmíràn, láti rí àwon òré, ebí

re, tàbí kí o yàn láti má bà Eni tí a pè léjó náà se papò? 7

1Ní ìlépa Átíkù kejì ti 2ECHR: a ó dáà àbò bo ètó tí enì kòòkan ní láti gbé ayé, CY Const. Art. 7 2Ní ìlépa Átíkù kaàrún ti 5ECHR: Enì kòòkan ní ètó sí òmìnira àti ààbò eni, CY Const. Art.11 3Ní ìlépa Átíkù kejo ti 8ECHR: Ètó eni kòòkan ni láti bòwò fún ìgbé ayé eni àti ti ebí rè, CY Const. Art. 15 4Ní ìlépa Átíkù kefa ti 6ECHR: Ètó sí Ìdájó òdodo, CY Const. Art. 30 5Ní ìlépa Átíkù kejo ti 8ECHR: Ètó eni kòòkan ni láti bòwò fún ìgbé ayé eni àti ti ebí rè, CY Const. Art. 15 6Ní ìlépa Átíkù kewaa ti 10ECHR: Òmìnira láti Sòrò, CY Const. Art. 19 7Ní ìlépa Átíkù kokànlá ti 11ECHR: Òmìnira láti kó egbé tó bá wun ni.

Page 6: ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLÈ FÚN ÀṢẸ ÀTÚ ̣E ... · Tó bá ku díè ̣káàtó fún ӑ, jòẉó ̣ri pé o párí Fóọ̀ṃù tó yӑ (O.8, R.1)

12. Sé o gbàgbó wí pé ìbéèrè fún ìdúró fún ni re láti pèsè àse láti dènà Eni

tí a pè léjó sí òdò re se pàtàkì kí èyí lè pèsè ààbò àti àtúnse láti dènà Eni

tí a pè léjó kó má bà á pa ètó omo ènìyàn àti òmìnira re lára? 8

BÉÈNI BÉÈKÓ

13. Sé lóòótó ni pé o kò fé kí Eni tí a pè léjó kàn sí e nítorí pé ó n dásí ètó

re sí òmìnira láti lo sí ibikíbi, tí èyí sì n pa ètó omo eniyan re lára? 9

14. Sé lóòótó ni pé àìfé Eni tí a pè léjó pèlú re bó se n dásí ètó re láti yan ibi

tó wùn é láti gbé n pa é lára? 10

15. Sé o gbàgbó lóòótó wí pé ìwà asemáse Eni tí a pè léjó tí o kò fé kó dásí

e, ó sì ti dérùbà é tàbí halè mó e láti lè má jé kí ó jègbádùn ayé re? 11

16. Sé o gbàgbó dáadáa wí pé àìfé Eni tí a pè léjó pèlú re yóò jásí ìdásí àwon

ètó re tí a ti ménubà lókè pèlú ní àwon nónbà wònyí (5), (6), (7), (9),

(10), (11), (12), (14), (15), àti (17) tó wà nísàlè tí yóò nílò kí ilé ejó fún

e ní àtúnse fún àse ìdáàbòbò pàjáwìrì? 12

17. Sé Eni tí a pè léjó ní àwon ohun ìjà olóró nílé, tàbí sé ó ní ànfààní sí

àwon ohun ìjà fún ìdí mìíràn tí wón sì ti dérùbà é rí nitorí pé Eni tí a pè

léjó ní ànfààní sí àwon ohun ìjà wònyí?

18. Sé o fé kí á dènà Eni tí a pè léjó láti lè máa bá e sòrò? 13

19. Sé o fé kí á dènà Eni tí a pè léjó láti máa bá àwon omo (to bá bímo rárá)

re sòrò nítorí ìdí tí a so ní (17)? 14

20. Sé o fé kí Eni tí a pè léjó lè kàn sí e, sùgbón lábé ètò ìkànsí/ìtójú re àti

àwon omo (Eni tí a pè léjó) tí a gbékalè?

21. Sé o gbàgbó wí pé kí á fún e ní àse ìdáàbòbò ní kíákíá yóò dí Eni tí a pè

léjó lówó láti dènà ewu tó lè fìyà je é gan?

22. Sé o ní ìgbàgbó tó péye wí pé nítorí àwon ìdí wònyí tó wà lókè, ó se

pàtàkì kí ilé ejó yára gbésè lé ohun ìní (tí ìwo àti Eni tí a pè léjó jo ní

tàbí èyí tí ó wà ní ìkáwó ... nítorí ìgbéyàwó) ebí re, yàtò sí èyí tí ìwo tàbí

Eni tí a pè léjó máa fi san owó oúnje, aso, ilé tó n gbé àti owó fún ìtójú

ara nílé ìwòsàn tàbí fún ètò èkó fún ìwo tàbí àwon omo re, nígbà tí ejó

yìí n lo lówó?

Tí ìdáhùn re bá jé béèni, kí o sàkoólè àwon ohun ìní tí e jo ní papò, kí o sì soómó

fóòmù Ìwé Òfin (O.2, R.1).

BÉÈNI

BÉÈKÓ

8Ní ìlépa Átíkù kerìnlálá ti 14ECHR:Eto si atunse to dan moran.. 9Ní ìlépa Ìlànà kerin ti Átíkù 2ECHR: Òmìnira láti rìn síbi tí o bá fé, CY Const. Art 13 10Ní ìlépa Ìlànà kerin ti Átíkù 2ECHR: Òmìnira láti rìn síbi tí o bá fé, CY Const. Art 13 11Ní ìlépa Ìlànà keje ti Átíkù 5ECHR: Ìdógba wà láàrin toko-taya. 12Ní ìlépa Átíkù kerinla ti 14ECHR: Ètó sí àtúnse tó dán mórán. 13Ní ìlépa Átíkù kejo ati kokanla ECHR, CY Const. Art.15 14Ní ìlépa Átíkù kejo ECHR àti Abala kìíní, nínú Átíkù kejì

Page 7: ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLÈ FÚN ÀṢẸ ÀTÚ ̣E ... · Tó bá ku díè ̣káàtó fún ӑ, jòẉó ̣ri pé o párí Fóọ̀ṃù tó yӑ (O.8, R.1)

OHUN ÌNÍ EBÍ, òwó so gbogbo àlàyé tó wà níbè (bó bá se bá lo)

i. Àkoólè Owó Nílé Ìfowópamó

ii. Ilé

iii. Ìsura Ojà

iv. Ohun Mìíràn

...............................................

................................................

.................................

FÓÒMÙ NONBA 45

ÌBÉÈRÈ FÚN TÓ DI ÌDÚRÓ FÚN NI (O.48, R.2)

Ní Ekùn Ilé Ejó ti ……………………… Nónbà ………………ni 20…..

Láàrin ………………………….A.B.,………………… Olùfisùn,

Àti

……………………………………….C.D.,……………… Eni tí a pè léjó.

Ìdúró Fún ni A.B., of……………………………………, Oníbèéèrè.

Oníbèéèrè òkè yìí n bèrè fún (a)………..……………..

Page 8: ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLÈ FÚN ÀṢẸ ÀTÚ ̣E ... · Tó bá ku díè ̣káàtó fún ӑ, jòẉó ̣ri pé o párí Fóọ̀ṃù tó yӑ (O.8, R.1)

Eni tó mú ejó wá n bèrè fún

Ìbéèrè náà tó dá lórí àse fún ìtura lábé Àse Kejìdínláàdóta, Òfin kejo, ìpínfò kìíní, lábé (ss) ti

Òfin Ìlànà Òfin Àwùjo.

* Àwon òtító tí ohun gbogbo dá lé lórí nìwònyí: (c)…………………………..

Tàbí

*( Àwon òtító tí ohun gbogbo dá lé lórí nínú ìbúra ti wà pèlú won nípasè

A.B. tí a déètì ………………………………………….)

Ìbéèrè fún tí A.B. bèrè fúnra rè (tàbí E.F.., agbejórò fún A.B.)

(A fowósí)

Agbejórò fún Eni tó Béèrè Fún Ìdájó.

A fì lé lè ní ........................... ojó ............. …………………, 20…………..

Tí ojó ìgbéjó jé .............. ……….. ojó .................... ……………………, 20…., ní ìwòn

aago………………. òsán.

Akòwé Àgbà Ilé Ejó,

(a) Sàgbékalè àse tàbí ìdarí tí a béèrè fún.

(b) Sàgbékalè abala Òfin tàbí Òfin Ilé Ejó kan ní pàtó.

(d) Tí a kò bá bèrè fún ìbéèrè fún náà láti jé kí ìbúra náà kó sàtìléyìn re, ká so òótó tí a gbáralé

náà nínú ìbéèrè fún náà.

* Fagilé e tí a kò bá bèrè fun.

Page 9: ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLÈ FÚN ÀṢẸ ÀTÚ ̣E ... · Tó bá ku díè ̣káàtó fún ӑ, jòẉó ̣ri pé o párí Fóọ̀ṃù tó yӑ (O.8, R.1)

FÓÒMÙ Nónbà Kìíní

ÌWÉ ÒFIN (O. 2, r. 1)

Ní Ekùn ............................. Nonba....................Ni 20…

Láàrin .......................A.B, .................... Olùfisùn,

Àti

............................C.D,........................ Eni tí a pè léjó.

Sí C.D. ti (a)....................................(b)...........................

Èyí ni láti pàse fún e wí pé láàrín ojó méwàá, léyìn tí o ti gba ìwé òfin yìí sówó, pé o ti

bèrè ejó pèlú A.B ti (a).......................................(c)................................

Ohun tí Olùfisùn n bèrè fún nínú isé náà ní a sàgbékalè nínú ìfowósí léyìn ìwé.

Àdírèsì ibi tí a máa mú ìwé lo sí fún Olùfisùn jé (d).................................

Kí o sì kíyèsí pé, tí o ba ko lati farahan ni ona ti a so si isale yii, Olùfisùn le tesiwaju,

won yóò sì se ìdájó láìsí e níbè.

A fi sínú fáìlì, a sì gbe léwòn ní (e).......................... ojó....................... ti

(A ti fowósi)

Akòwé Àgbà Ilé Ejó.

ÀKÍYÈSÍ —Ìfarahàn lè wáyé nípa pé kí olùfisùn fúnra rè wá tàbí kí agbejórò rè wá

sódò Akòwé Àgbà Ilé Ejó ní (f)............ Kí wón se ìwé ìránilétí pé ó wá, láti fí jérìí

àdírèsì Olùfisùn, kí wón sì fi déètì si lójó náà, kí ó lè wà gégé bí èdà fún ojó mìíràn, kí

Akòwé Àgbà Ilé Ejó sì fowósi pèlú èdìdí.

_____________________________________

(a) Ko àdírèsì ní kíkún kí o so orúko àdúgbò àti nónbà ilé náà tó ba ní.

(b) (b) So isé tí Eni tí a pè léjó n se tí o bá mò ó.

(c) So isé tí Olùfisùn n se.

(d) Fún won ní orúko kikun, ise ati adiresi eni tó n gbé ní agbègbè tó súnmó ìlú tàbí abúlé ibi tí nnkan tí

ìsèlè náà, tí a lè fún ní àkosílè tí a fé fún Olùfisùn náà ní kíkún.

(e) Akòwé Àgbà Ilé Ejó ní kó ko déètì náà.

(f) Dárúko ìlú tàbí abúlé tí ibi ìforúkosílè tí a sàpèjúwe (d) lókè yìí wà.

KÍYÈSÍ —Tí o bá fé sàgbékalè ìwé òfin, ká kíyèsí láti wo ohun tí Àse Kejí tí a pèsè àti àwon àse tó n darí

ìfowósí so.

Àkíyèsí fún Eni tí a pè léjó— Eni tí a pè léjó tó fé gba agbejórò, gbódò fi sókàn wí pé, àyàfi tí adájó bá lo kúrò agbejórò kò lè dúró fun, àfi tí a bá ti fun ní àse nínú ìwé tí a ko nínú Fóòmù 12A, tí Eni tí a pè léjó sì

ti Fowósí.

Page 10: ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLÈ FÚN ÀṢẸ ÀTÚ ̣E ... · Tó bá ku díè ̣káàtó fún ӑ, jòẉó ̣ri pé o párí Fóọ̀ṃù tó yӑ (O.8, R.1)

Ìfowósí Ètó

Ètó Olùfisùn jé

(A ti fowósi)

__________________________________________

(a) Agbejórò fún Olùfisùn.

__________________________________________________

(a) Fagilé "Agbejórò fún" tí o bà n gba ejó ara re rò.

Page 11: ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLÈ FÚN ÀṢẸ ÀTÚ ̣E ... · Tó bá ku díè ̣káàtó fún ӑ, jòẉó ̣ri pé o párí Fóọ̀ṃù tó yӑ (O.8, R.1)

Ìbéèrè fún Ìgbéjó fún Eni Tó Kù Díè Káàtó Fún (O.8, R.1)

Ní Ekùn Ilé Ejó ti ……………….. Nónbà

_________________Olùfisùn

ÀTI

_________________Eni tí a pè

léjó

Eni tó n bèrè fún nnkan ti fi Ìbéèrè fún ìdúró fún ni nonba 45 ránsé fún ìtura àse

ní________________. (déètì)

Eni tó n bèrè fún nnkan so wí pé òún n pe ejó gégé bí eni tó kù díè káàtó fún, fún

àwon ìdí wònyí lábé Àse kejo, Òfin Kìíní ti Òfin Ìlànà Òfin:

(i) wí pé òun kò ní tó ìwòn iye €171 (yàtò sí aso tí òun wò, ibùsùn àti òrò

tó wà nílè yìí);

(ii) wí pé gbogbo owó tó n wolé sí òun lówó lósóòsè kò kojá €9; àti

(iii) òun ní àwon ìdí tó ye láti pe eni òun léjó tàbí láti jé ejó òun.

Eni tó n bèrè fún nnkan fi lélè pèlú Ìbúra láti lè fi ti àwon gbólóhùn tó wà lókè yìí

léyìn fún ìbéèrè fún yìí.

Orúko:

A fi lélè ní ____________ Ìgbówónsí:

AKÒWÉ ÀGBÀ ILÉ EJÓ

Page 12: ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLÈ FÚN ÀṢẸ ÀTÚ ̣E ... · Tó bá ku díè ̣káàtó fún ӑ, jòẉó ̣ri pé o párí Fóọ̀ṃù tó yӑ (O.8, R.1)

ÌBÚRA

Èmi,……………………………………………………………………………………

……. láti ………………………………………………………… àti eni tó ni Pálí

Ìrìnàjò/Káàdì Àlejò/ Káàdì Ìdánimò pèlú nónbà.………………………………. .... Mo

búra, mo sì so àwon nnkan wònyí:

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

…………………………………………………………………………………………

………………………………………………………………………………………….

ENI ÌBÚRA NÁÀ

………..………..………….……………

Won búra, wón sì fi owó si níwájú mi

sí Ekùn Ilé Ejó ti ……………………..

Lónìí …………………………………..

AKÒWÉ ÀGBÀ ILÉ EJÓ

Page 13: ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLÈ FÚN ÀṢẸ ÀTÚ ̣E ... · Tó bá ku díè ̣káàtó fún ӑ, jòẉó ̣ri pé o párí Fóọ̀ṃù tó yӑ (O.8, R.1)

FÓÒMÙ KAÀRÚN

ÌBÚRA ÌFI ÀKOSÍLÈ JÍSÉ (O.5, R.2)

Èmi, …………………………… tí mo jé apèsè ìlànà, búra, mo sì wí pé mo ti pèsè èdà

ìwé ofin ti ofiisi. …………………… ti …………………... Ibi Ìforúkosílè, ní (a)

…………………………. ni……………. ojó …………20....., mo si fi sílè níwájú

............... pèlú Eni tí a pè léjó

(b)……………………..(c)………………… fún Eni tí a pè léjó

……………………… eni tí mo ò bá nílé rè tàbí níbi isé rè tí a mò ó mó, (d)

……………………………………………. ìyen eni tí a pè léjó náà

Èdà (àwon) àkosílè tí a ti fi jísé ní a somó níbí gégé bí èrí mo sì sàmì "A" sí lára

tàbí

Pé ìbúra yìí wà lórí èdà àkosílè tí a ti fi jísé.

Wón fowósí, wón sì búra níwájú mi …………………………………………

ní ………………… ní ……………………….. ojó ………………………

ti…………………..20…..

A ti fowósi

…………………...........

……………………… Akòwé Àgbà Ilé Ejó.

______________________________________________

(a) Ìlú tàbí abúlé tí ìjísé náà kan

(b) Fagilé "Eni tí a pè léjó" tí kò bá kàn án,

(c) Fagilé gbogbo rè dé òpin tí kò bá ní ohun kankan se pèlú rè

(d) So ìbásepò re pèlú Eni tí a pè léjó eni tí a fi ìwé òfin náà sílè fún

Kíyèsi. – A gbódò se ìbúra ìfi létà jísé yìí láàrin ojó méje léyìn tí a bá ti fi àkosílè

jísé tán.

Page 14: ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLÈ FÚN ÀṢẸ ÀTÚ ̣E ... · Tó bá ku díè ̣káàtó fún ӑ, jòẉó ̣ri pé o párí Fóọ̀ṃù tó yӑ (O.8, R.1)

Ìkaàrún – Ìbúra Ìfi Àkosílè Jísé (ti Kòtémilórùn)

Èmi................................................................... tí mo jè apèsè ìlànà, búra, mo sì wí pé

mo ti pèsè èdà ìpèléjó kòtémilórùn ofiisi sí èdà ìpinnu yìí (tàbí Àse) nínú ……..……..

Ibi ìforúkosílè,

ti (a) ……………………………………………………………………………………

ni…………………….20 ………., mo sì fi ohun kan náà sílè níwájú u

…………………………………….. láti …………………………….. lo sí òdò Eni Tó

Dáhùn (b) …………………………………………………………………

(c)………………………………………………………… ti

………………………………….. lo sí òdò Eni Tó Dáhùn ……………………………

eni tí Èmi kò bá ní ilé rè tàbí ibi isé rè gégé bí a ti se so

(d)…………………………………………………………………. Nipa re

A fowósí Ìbúra yìí wa lórí èdà àkosílè tí a ti fi jísé.

(Fowósi.)

Wón fowósi, wón sì búra níwájú mi ………………………… ní ………………...

Akòwé Àgbà Ilé Ejó.

Page 15: ÌBÉÈRÈ FÚN ÀTI ÌFIKÚN LÁTI FI FÁÌLÌ LÉLÈ FÚN ÀṢẸ ÀTÚ ̣E ... · Tó bá ku díè ̣káàtó fún ӑ, jòẉó ̣ri pé o párí Fóọ̀ṃù tó yӑ (O.8, R.1)

Àwon ìdí tí mo fi n pe ejó kòtémilórùn ni pé: Ilé Ejó Ko Ìbéèrè Fún mi.

(a) Wo Fóòmù tí a Somo, tí mo fi pe ejó ní Ilé Ejó yìí fún Ìbéèrè Fún Ìdúró Fún Ni

Fún Àse Ìdáàbòbò Láti má Kàn sí i fún ìtura tí mo bèrè fún.

(Fowósi)

Agbejórò fún ………….

A fi lélè ní ………………

Akòwé Àgbà Ilé Ejó

Ojúlówó Èdà tí a Fowósí