fun ilewo yi, ekan si: ewe moringa alaragbayida •gbin igi kan •fi ewe gigun sinu ounje re •se...

2
Alaragbayida ni ede gbogbo... Bengali: Sajna Burmese: Dandalonbin French: Bèn ailé, Benzolive Gujarati: Suragavo Hindi & Urdu: Munaga, Sahijna, Segra Khmer: Daem mrum Malay: Kalor Malayalam: Sigru, Muringa Marathi: Sujna, Shevga Oriya: Munigha, Sajina Punjabi: Soanjana Sinhalese: Murunga Spanish: Ben, Morango, Moringa Tagalog: Mulangai Tamil: Murungai Telegu: Munaga, Mulaga Thai: Marum Vietnamese: Chùm Ngây Trees for Life n ro awon eniyan ni agbara nipa sise afihan pe ninu iranra-eni-lowo ni oun mere- mere ma n jade to le fi oyin si aye wa. O rorun lati gbin: Ewe Moringa Alaragbayida •Gbin igi kan •Fi ewe gigun sinu ounje re •Se itankale ifilo yi pelu awon eniyan ki a le jumo ran ara wa lowo lati bunkun gbigbe aye ilera. • Pelu irugbin tabi igi • Paapaa ninu ile • Itoju die lo nilo • Omi die lo nilo • Yoo hu eso ati ewe laarin osu mejo O rorun lati lo: •Fi ewe tutu tabi ewe gbigbe kun ounje sise •Sa ewe (labe iboji) ki o si toju re •Iwon giraamu mejo si merinlelogun ewe gigun lojumo n fi kun ilera www.treesforlife.org/moringa Fun ilewo yi, ekan si: Je alaragbayida! (ewe igbale) Oruko ni egbo igi sayensi Botanical name: Moringa oleifera Ti opolopo n pe ni “ewe igbale” ni Yoruba. (Gbin in jina si ile, nitori won le se okunfa kokoro) Fun oruko ni ede miran: www.treesforlife.org/moringa/names www.treesforlife.org Trees for Life, 3006 W. St. Louis, Wichita, KS 67203-5129 USA Phone: (316) 945-6929 Fax: (316) 945-0909 [email protected] Alaragbayida ni ede gbogbo... Bengali: Sajna Burmese: Dandalonbin French: Bèn ailé, Benzolive Gujarati: Suragavo Hindi & Urdu: Munaga, Sahijna, Segra Khmer: Daem mrum Malay: Kalor Malayalam: Sigru, Muringa Marathi: Sujna, Shevga Oriya: Munigha, Sajina Punjabi: Soanjana Sinhalese: Murunga Spanish: Ben, Morango, Moringa Tagalog: Mulangai Tamil: Murungai Telegu: Munaga, Mulaga Thai: Marum Vietnamese: Chùm Ngây Trees for Life n ro awon eniyan ni agbara nipa sise afihan pe ninu iranra-eni-lowo ni oun mere- mere ma n jade to le fi oyin si aye wa. O rorun lati gbin: Ewe Moringa Alaragbayida •Gbin igi kan •Fi ewe gigun sinu ounje re •Se itankale ifilo yi pelu awon eniyan ki a le jumo ran ara wa lowo lati bunkun gbigbe aye ilera. • Pelu irugbin tabi igi • Paapaa ninu ile • Itoju die lo nilo • Omi die lo nilo • Yoo hu eso ati ewe laarin osu mejo O rorun lati lo: •Fi ewe tutu tabi ewe gbigbe kun ounje sise •Sa ewe (labe iboji) ki o si toju re •Iwon giraamu mejo si merinlelogun ewe gigun lojumo n fi kun ilera www.treesforlife.org/moringa Fun ilewo yi, ekan si: Je alaragbayida! (ewe igbale) Oruko ni egbo igi sayensi Botanical name: Moringa oleifera Ti opolopo n pe ni “ewe igbale” ni Yoruba. (Gbin in jina si ile, nitori won le se okunfa kokoro) Fun oruko ni ede miran: www.treesforlife.org/moringa/names www.treesforlife.org Trees for Life, 3006 W. St. Louis, Wichita, KS 67203-5129 USA Phone: (316) 945-6929 Fax: (316) 945-0909 [email protected]

Upload: vohanh

Post on 01-Apr-2018

264 views

Category:

Documents

9 download

TRANSCRIPT

Page 1: Fun ilewo yi, ekan si: Ewe Moringa Alaragbayida •Gbin igi kan •Fi ewe gigun sinu ounje re •Se itankale ifilo yi pelu awon eniyan ki a le jumo ran ara wa lowo lati bunkun gbigbe

Alaragbayida ni ede gbogbo...

Bengali: SajnaBurmese: Dandalonbin French: Bèn ailé, BenzoliveGujarati: SuragavoHindi & Urdu: Munaga, Sahijna, SegraKhmer: Daem mrumMalay: KalorMalayalam: Sigru, MuringaMarathi: Sujna, ShevgaOriya: Munigha, SajinaPunjabi: SoanjanaSinhalese: MurungaSpanish: Ben, Morango, MoringaTagalog: Mulangai Tamil: MurungaiTelegu: Munaga, MulagaThai: MarumVietnamese: Chùm Ngây Trees for Life n ro awon eniyan ni agbara nipa sise

afihan pe ninu iranra-eni-lowo ni oun mere- mere ma n jade to le fi oyin si aye wa.

O rorun lati gbin:

Ewe Moringa Alaragbayida

•Gbin igi kan•Fi ewe gigun sinu ounje re•Se itankale ifilo yi pelu awon eniyan ki a le jumo ran ara wa lowo lati bunkun gbigbe aye ilera.

• Pelu irugbin tabi igi• Paapaa ninu ile• Itoju die lo nilo• Omi die lo nilo• Yoo hu eso ati ewe laarin osu mejo

O rorun lati lo:•Fi ewe tutu tabi ewe gbigbe kun ounje sise•Sa ewe (labe iboji) ki o si toju re•Iwon giraamu mejo si merinlelogun ewe gigun lojumo n fi kun ilera

www.treesforlife.org/moringa

Fun ilewo yi, ekan si:

Je alaragbayida!

(ewe igbale)

Oruko ni egbo igi sayensi Botanical name: Moringa oleiferaTi opolopo n pe ni “ewe igbale” ni Yoruba.

(Gbin in jina si ile, nitori won le se okunfa kokoro)

Fun oruko ni ede miran: www.treesforlife.org/moringa/names

www.treesforlife.orgTrees for Life, 3006 W. St. Louis, Wichita, KS 67203-5129 USA Phone: (316) 945-6929 Fax: (316) [email protected]

Page 2: Fun ilewo yi, ekan si: Ewe Moringa Alaragbayida •Gbin igi kan •Fi ewe gigun sinu ounje re •Se itankale ifilo yi pelu awon eniyan ki a le jumo ran ara wa lowo lati bunkun gbigbe

Potassium se pataki fun opolo ati isan wa. Sugbon bi ogede se kun fun potassium to, ewe Moringa dara juu lo.

Vitamin A maa n duro bii idaabobo fun oju, ara ati okan lowo igbe gbuuru (diarrhea) ati awon ailera miran. Sugbon bi Karooti se kun fun opolopo Vitamin A to, ewe Moringa yoo fun wa jubeelo

Vitamin C ma n ro arawa lagbara, o si ma n koju ija si orisirisi arun bii otutu ati kooli. O wa se ni kayefi pe ewe Moringa kun fun vitamin C ju osan ati ganyinganyin lo.

Kayeefi, sugbon otito!Puroteeni, ti o je bulooku amuto ara wa kun fun amino acids. Lopo igba, a ma n ri lara ohun elo eranko bii eran, eyin ati bee bee lo. Owa ya ni lenu wipe ewe Moringa naa kun fun:

Ilopo Merin Calcium inu Miliiki

Calcium maa n mu egungun ati eyin nipon daadaa, o si n gbogun ti arumoleegun. Miliiki maa n seda Calcium lopo, sugbon o ewe Moringa n pese lopolopo.

Ilopo Meje vitamin C ninu osan.

Ilopo Meji puroteeni inu yugooti

Akosile wonyii n se afiwe oni-giramu-fun-giramu pelu ewe Moringa*

Laye ode oni, awon onimo sayensi ti fihan pe ewe Moringa kun fun opolopo ohun elo ara aseniloore ti yoo ro ara wa lagbara ti yoo si tun dena opolopo arun.

Lati aye atijo ni won tin wipe “Ewe Moringa le dena eedegbeta arun”

Afiwe ewe Moringa pelu awon ounje ojoojumo*

*Nutritive Value of Indian Foods, by C. Gopalan, et al, and The Miracle Tree – Moringa oleifera: Natural Nutrition for the Tropics, by Lowell Fuglie, ed. Fun alaye lekunrere: www.treesforlife.org/moringa

Vitamin A Vitamin B1 Vitamin B2 Vitamin B3 Vitamin C Calcium Chromium Copper Fiber Iron Manganese Magnesium Phosphorus Potassium Protein Zinc

Ilopo Meta potassium inu ogede

Ilopo Merin vitamin A inu karooti

O dabi igba ti a ba n gbin ohun elo asara lore si enu ona wa ni.

ErojaIsaraloore

Ounje ati eso Ewe tutu Ewe gbigbe

Vitamin A

Calcium

Potassium

Protein

Vitamin C

Miligiraamu 1.8 karooti

Miligiraamu120 miliiki

Miligiraamu 88 ogede

Giraamu 3.1 yugooti

Miligiraamu 30 Osan

Miligiraamu6.8

Miligiraamu440

Miligiraamu259

Giraamu6.7

Miligiraamu 220

Miligiraamu18.9

Miligiraamu2003

Miligiraamu1324

Giraamu27.1

Miligiraamu 17.3