idariji

2
IDARIJI Ò rúnmìlà mo pe, Ò rúnmìlà mo pe, Ò rúnmìlà mo pe. Ifá mo pe, Ifá mo pe, Ifá mo pe. Oduduwa mo pe, Oduduwa mo pe, Oduduwa mo pe. Igi nla subu wona-kankan d'etu. Ò rúnmìlà ni o di adariji. Mo ni o di adariji. - (curvar-se em forma de Ikunlé – de joelho) Mo ni o di adariji. - (curvar-se em forma de Ikunlé – de joelho) Mo ni o di adariji. - (curvar-se em forma de Ikunlé – de joelho) A dariji, o ni bi Edan ba pa ni tan. A dariji, o ni bi Èsú-Odará ba pa ni tan. O ni bi O ya ba pa ni tan. A ki i, a sa a, a f'ake eran fun ú. A dariji o ni bi S ango ba pa ni tan. A ki i, a sa, a f'agbo fun u. A dariji, o ni bi Ògún ba pa ni tan. A dariji, o ni bi Obatala ba pa ni tan. A dariji, o ni bi Yeye-Òsún ba pa ni tan. A dariji, o ni bi Iyaami Èlèyé ródanú, ba pa ni tan. A dariji, o ni bi Baba-Èégùn Òlògbójó ba pa ni tan. A dariji, o ni bi Òrí inu is és é, ba pa ni tan. A dariji, o ni bi Òrí mi ba pa ni tan. A ki i, a sa a, a f'aja fun u, a dariji, Oduduwa dariji wa bi

Upload: nel

Post on 11-Jan-2016

212 views

Category:

Documents


0 download

TRANSCRIPT

Page 1: IDARIJI

IDARIJI

Òrúnmìlà mo pe, Òrúnmìlà mo pe, Òrúnmìlà mo pe.Ifá mo pe, Ifá mo pe, Ifá mo pe.Oduduwa mo pe, Oduduwa mo pe, Oduduwa mo pe.Igi nla subu wona-kankan d'etu. Òrúnmìlà ni o di adariji.Mo ni o di adariji. - (curvar-se em forma de Ikunlé – de joelho)Mo ni o di adariji. - (curvar-se em forma de Ikunlé – de joelho)Mo ni o di adariji. - (curvar-se em forma de Ikunlé – de joelho)A dariji, o ni bi Edan ba pa ni tan.A dariji, o ni bi Èsú-Odará ba pa ni tan.O ni bi Oya ba pa ni tan.A ki i, a sa a, a f'ake eran fun ú. A dariji o ni bi Sango ba pa ni tan.A ki i, a sa, a f'agbo fun u. A dariji, o ni bi Ògún ba pa ni tan.A dariji, o ni bi Obatala ba pa ni tan.A dariji, o ni bi Yeye-Òsún ba pa ni tan.A dariji, o ni bi Iyaami Èlèyé ródanú, ba pa ni tan.A dariji, o ni bi Baba-Èégùn Òlògbójó ba pa ni tan.A dariji, o ni bi Òrí inu isésé, ba pa ni tan.A dariji, o ni bi Òrí mi ba pa ni tan.A ki i, a sa a, a f'aja fun u, a dariji, Oduduwa dariji wa bi A ti ndariji awon ti o se wa. Ase.